Movatterモバイル変換


[0]ホーム

URL:


Jump to content
Wikipedia
Ṣe àwáàrí

Zulu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Bodie September 2016 019
Zulus
Àpapọ̀ iye oníbùgbé
10,659,309 (2001 census)[1]
Regions with significant populations
 Gúúsù Áfríkà
KwaZulu-Natal7.6 million[1]
Gauteng1.9 million[1]
Mpumalanga0.8 million[1]
Free State0.14 million[1]
Èdè

Zulu
(many also speakEnglish,Afrikaans,Portuguese, or other indigenous languages such asXhosa)

Ẹ̀sìn

Christian,African Traditional Religion

Ẹ̀yà abínibí bíbátan

Bantu ·Nguni ·Basotho ·Xhosa ·Swazi ·Matabele ·Khoisan

ZuluÀwọn ènìyàn Zulu ni ẹ̀yà tó pọ̀jù ni orílè-èdèGúúsù Áfríkà. A mọ̀ wọ́n mọ́ ìlẹ̀kẹ̀ alárànbàrà àti agbọ̀n pẹ̀lú àwọn ñǹkan gbígbẹ́. Wọ́n gbàgbọ́ pé àwọn jẹ́ ìran tó sẹ̀ lára olóyè kan láti agbègbè Cóńgò, ni ñǹkan ẹgbẹ̀rún ọdùn mẹ́rìndínlógún sẹ́yìn ni wọn tẹ̀síwájú sí Gúsú. Àwọn ènìyàn Zulu gbàgbọ́ nínú òrìṣà tó ń jẹ́ Nkulunkulu gẹ̀gẹ́ bí asẹ̀dá wọn òrishà yìí ko ní àjọsepọ̀ pẹ̀lú ènìyàn bẹ́ẹ̀ ni kò ní ìfẹ́ sí ìgbé ayé kọ̀ọ̀kan. Awọn ènìyàn Zulu pin sí méjì! àwọn ìlàjì ni inú ìlù nígbà tí àwọn ìlàjì yókù sì wà ní ìgberíko tí wọ́n ń ṣisẹ́ àgbẹ̀. Mílíònù mẹ́sàn-án ènìyàn ló ń sọ èdè Zulu. Èdè yìí jẹ́ ọ̀kan lára àwọn èdè ìjọba mọ́kànlá ilẹ̀ South Africa. Àkọtọ Rómàniù ni wọ́n fi ń kọ èdè náà.



Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí.

Ẹ lefẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ látifẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ.

  1. 1.01.11.21.31.4South Africa grows to 44.8 million, on the sitesouthafrica.info published for the International Marketing Council of South Africa, dated 9 July 2003, retrieved 4 March 2005.
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/w/index.php?title=Zulu&oldid=556459"
Àwọn ẹ̀ka:
Ẹ̀ka bíbòmọ́lẹ̀:

[8]ページ先頭

©2009-2025 Movatter.jp