Yola
Àwọn irinṣẹ́
Àpapọ̀
Ìtẹ́síìwé/ìkójáde
Ní àkànṣe iṣẹ́ míràn
Yola di olú-ìlú àti ìlú tí ó tóbi jù ní fÌpínlẹ̀ Adamawa,Nàìjíríà. Ìlú náà wà ní olùgbé 336,648 ní ọdun 2010.[1] Yola pín sí méjì, àwọn ni ìlú Yola àtijó níbi tí Lamido ìlú náà gbé àti ìlúJimeta, ìlú Jimeta ní àárín ètò ọ̀rọ̀ ajé Yola.
![]() | Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ lefẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ látifẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
9°14′N12°28′E / 9.23°N 12.46°E /9.23; 12.46