Movatterモバイル変換


[0]ホーム

URL:


Jump to content
Wikipedia
Ṣe àwáàrí

Yinka Ajayi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Òrọ̀ ẹni
Ọjọ́ìbí11 Oṣù Kẹjọ 1997 (1997-08-11) (ọmọ ọdún 27)
Offa,Kwara State,Nigeria[1]
Height1.70 m
Weight59 kg
Sport
Orílẹ̀-èdè Nigeria
Erẹ́ìdárayáAthletics
Event(s)400 m
Achievements and titles
Highest world ranking58
Personal best(s)400 m: 51.22 s (2018)
Updated on 28 February 2019.

Yinka Ajayi (tí wọ́n bí ní 11 August 1997) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdèNàìjíríà tó máa ń kópa nínú ìdíje eré sísà ti irinwó mítà.[2] Òun ló gba àmì-ẹ̀yẹ onídẹ fún ìdíje 2018 African Championships in Asaba. Nínú ìdíje tó kópa nínú, ó gba àmì-ẹ̀yẹ onídẹ nínú ìdíje 2017 Islamic Solidarity Games, tó jẹ́ àfikún sí àwọn ìdíje mìíràn. Ọmọ ìyá kan náà ni oùn àtiMiami Dolphins tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́;Jay Ajayi.

Òun ló gba àmì-ẹ̀yẹ onífàdákà fún ipò keji tó gbé nínú ìdíje irinwó mítà ní 2018 Commonwealth Games, Ó sì tún kópa nínú ìdíje 4 × 400 m (Patience George,Glory Nathaniel,Praise Idamadudu, Ajayi), èyí sì mu kí ó gé ipò kejì, tí ó sì gba àmì-ẹ̀yẹ onífàdákà.

Ó gbé ipò kejì nínú ìdíje 2017 Nigerian Championships, èyí sì ní ìdíje rẹ̀ tó dára jù, tó sá eré fún ìṣẹ́jú àáyá 51.57, pẹ̀lúPatience George ní ẹ̀yìn rẹ̀.[3] Ó kópa nínú ìdíje irinwó mítà nínú 2017 IAAF World Championships. Ìdíje rẹ̀ tó dára jù ni èyí tó sá fún ìṣẹ́jú àáyá 51.22 ní ìlúAbuja, ní 2018 Abuja Golden League.[4]

Àwọn ìdíje rẹ̀ nínú ìdíje àgbáyé

[àtúnṣe |àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Aṣojú fúnNàìjíríà Nàìjíríà
2014World Junior ChampionshipsEugene, United States5th4 × 400 m relay3:35.14
2015African Junior ChampionshipsAddis Ababa, Ethiopia1st4 × 400 m relay3:38.94
2016African ChampionshipsDurban, South Africa11th (sf)400 m53.54
2nd4 × 400 m relay3:29.94
2017Islamic Solidarity GamesBaku, Azerbaijan3rd400 m52.57
2nd4 × 100 m relay46.20
2nd4 × 400 m relay3:34.47
World ChampionshipsLondon,United Kingdom19th (sf)400 m52.10
5th4 × 400 m relay3:26.72
2018Commonwealth GamesGold Coast,Australia8th400 m52.26
2nd4 × 400 m relay3:25.29
African ChampionshipsAsaba, Nigeria3rd400 m51.34
1st4 × 400 m relay3:31.17
2019World RelaysYokohama, Japan18th (h)4 × 400 m relay3:32.10

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe |àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "2018 CWG bio". Retrieved30 April 2018. 
  2. Àdàkọ:World Athletics
  3. Maduewesi, Christopher (2017-07-15)."Arowolo, Okon-George & Nathaniel win titles at National Championships".MAKING OF CHAMPIONS. Retrieved2017-08-11. 
  4. Olus, Yemi (2018-03-18)."Ogunlewe, Ajayi & Ogundiran shine on Day 2 of Abuja Golden League".MAKING OF CHAMPIONS (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved2019-02-28. 
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/w/index.php?title=Yinka_Ajayi&oldid=585446"
Ẹ̀ka:

[8]ページ先頭

©2009-2025 Movatter.jp