English is the official language of at least twenty-eight states—some sources give a higher figure, based on differing definitions of "official." English andHawaiian are both official languages in the state ofHawaii.
English is thede facto language of American government and the sole language spoken at home by 82% of Americans age five and older.Spanish is the second most commonly spoken language.
Sometimes listed as fourth largest in area; the rank isdisputed withChina (PRC). The U.S. figure includes only the fifty states and the District of Columbia, not the territories.
The population estimate includes people whose usual residence is in the fifty states and the District of Columbia, including noncitizens. It does not include either those living in the territories, amounting to more than four million U.S. citizens (most inPuerto Rico), or U.S. citizens living outside the United States.
Pelu 3.79 egbegberun ilopomeji maili (9.83 million km2) ati iye to ju 309 egbegberun eniyan lo, awon Ipinle Aparapo je orile-ede totobijuloketa tabi kerin bii apapo iye aala, ati iketa totobijulo biiaala ile ati bi awonolugbe. O je kan ninu awon orile-ede agbaye to niopolopo eya eniyan atiasapupo, eyi je nitori ikoreokere lati opo awon orile-ede.[6]Okowo awon Ipinle Aparapo ni okowo orile-ede to tobijulo lagbaye, pelu idiyeGIO 2009 to je $14.3 egbegberunketa (idamerinGIO oloruko lagbaye ati idamarun GIO agbaye funipin agbara iraja).[7]
Awon eniyan abinibi ti won wa latiAsia ti budo si ori ibi ti orile-ede awon Ipinle Aparapo wa loni fun egberun lopo odun. Awon olugbeAbinibi ara Amerika din niye gidigidi nitori arun ati igbogunti leyinibapade awon ara Europe. Orile-ede awon Ipinle Aparapo je didasile latowo awonileamusin metala ti Britani to budo si egbe Okun Atlantiki. Ni ojo 4 Osu Keje, 1776, won seIfilole Ilominira, eyi kede eto won fun iko araeni ati idasile isokan alafowosowopo won. Awon ipinle asagun yi boriIleobaluaye Britani ninuOgun Ijidide Amerika, eyi ni ogun alamusin fun ilominira akoko to yori si rere.[8]Ilana-ibagbepo ile awon Ipinle Aparapo lowolowo je gbigba bi ofin ni ojo 17 Osu Kesan, 1787; itowobosi ni odun to tele so awon ipinle di apa orile-ede olominira kan na pelu ijoba apapo to lagbara. AwonIsofin awon Eto, to ni atunse mewa si ilana-ibagbepo ti won semudaju awon eto ati ainidekun araalu, je titowobosi ni 1791.
Ni 1507,Martin Waldseemüllerayamaapu ara Jemani pese maapu lori ibi to ti pe oruko awon ile ti won wa niIbiilaji Apaiwoorun bi"Amerika" lati inu oruko oluwakiriri ati ayamaapu ara ItaliaAmerigo Vespucci.[11] Awon ibiamusin Britani tele metala koko lo oruko orile-ede yi ninuIfilole Ilominira, bi "Ifilole alafenuko awon Ipinle aparapo ile Amerika" ("unanimous Declaration of the thirteen united States of America") to je gbigba mu latowo "Awon Asoju awon Ipinle aparapo ile Amerika" ("Representatives of the united States of America") ni ojo 4 Osu Keje, 1776.[12] Ni ojo 15 Osu Kokanla, 1777, Ipejo Olorile Keji gba awon Ese-oro Ikorapapo, to so pe, "Oruko Ijekorapapo yi yio je 'Awon Ipinle Aparapo ile Amerika'" ("The Stile of this Confederacy shall be 'The United States of America.'") Awon iwe adehun lari Fransi ati Amerika odun 1778 lo "Awon Ipinle Aparapo ile Ariwa Amerika ("United States of North America"), sugbon lati ojo 11 Osu Keje, 1778, "Awon Ipinle Aparapo ile Amerika" ("United States of America") lo je lilo lori awon owo fun pasiparo, latigbana eyi lo ti je oruko onibise re.[13]
Ni ede Yoruba "Orile-ede Amerika" tabi "Amerika" lasan loruko to wopo. A tun le lo lo "U.S." tabi "USA".
Awon araalu awon Ipinle Aparapo ile Amerika la mo bi awon ara Amerika.[14]
Aworan aruleyin to unfihanojuile orile-ede Amerika
Amerika ni bode po mo Kanada, to gun lapapo to 8895 km (pelu bode larin Kanada ati Alaska to to 2477 km), o tun ni bode mo Meksico, to gun to 3326 km. Iye apapo igun bode Amerika je 12,221 km. Bakanna etiodo moAtlantiki,Pasifiki atiIkun-omi Meksiko na tun ni iye apapo to to 19,924 km.
Aala ori ile Amerika je 9,161,924 km2 pelu aala ori omi to to 664,706 km2, gbogbo aala ile Amerika je 9.82663 egbegberun km2[15].
Ifagun ariwa-guusu re lati bode mo Kanada ati bode mo Meksiko je 2,500 km, ifagun ilaorun-iwoorun lati eti Okun Atlantiki de Psifiki je 4,500. Orile-ede Amerika dubule si arinilagbolojo apaariwa 24 ati 49 ati larinilaninaro apaiwoorun 68th ati 125, be sini o pin siakókò ilẹ̀àmùrè merin.
Ojuojo duro lori ibudo. Lati ileolooru niFlorida titi detundra niAlaska. Opo ibi ni won ni ooru ni igba eerun ati otutu ni igba oye. Awon ibomiran tun wa biCalifornia ti won ni ojuojoMediteraneani. Ojuojo oloro ko wopo. Awon ipinle ti won bode moIkun-omi Meksiko ni iji are prone to hurricanes, and most of the world's tornadoes occur within the country, mainly in the Midwest's Tornado Alley.[16]
↑Adams, J. Q., and Pearlie Strother-Adams (2001).Dealing with Diversity. Chicago: Kendall/Hunt.ISBN 0-7872-8145-X.
↑TheEuropean Union has a larger collective economy, but is not a single nation.
↑Dull, Jonathan R. (2003). "Diplomacy of the Revolution, to 1783," p. 352, chap. inA Companion to the American Revolution, ed. Jack P. Greene and J. R. Pole. Maiden, Mass.: Blackwell, pp. 352–361.ISBN 1-4051-1674-9.
↑Wilson, Kenneth G. (1993).The Columbia Guide to Standard American English. New York: Columbia University Press, pp. 27–28.ISBN 0-231-06989-8.
↑Lubowski, Ruben, Marlow Vesterby, and Shawn Bucholtz (2006-07-21)."AREI Chapter 1.1: Land Use". Economic Research Service. Archived fromthe original on 2006-08-08. Retrieved2009-03-09.CS1 maint: Multiple names: authors list (link)