Movatterモバイル変換


[0]ホーム

URL:


Jump to content
Wikipedia
Ṣe àwáàrí

UNICEF

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àjọ àwọn Orílẹ̀-èdè Aparapọ̀ fún àwọn Ọmọdé
United Nations Children's Fund
IrúFund
OrúkọkúkúrúUNICEF
OlóríAnn Veneman
IpòActive
Dídásílẹ̀December 1946
Ibiìtakùnhttp://www.unicef.org
ÒbíECOSOC

Ki ni UNICEF

[àtúnṣe |àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

UNICEF ní èdè gẹ̀ẹ́sì dúró fúnUnited Nations Children's Fund (Àjọ Ìṣọ̀kan àwon Orílẹ̀-èdè fún àwọn Ọmọdé). Wọ́n sì jẹ́ ara àwọn àjọ tí ań pè ní (NGOs) ní èdèe gẹ̀ẹ́sì. Àwọn àjọ yìí (NGOs) jẹ́ àjọ aládàníi fún ìtẹ̀síwájú ọ̀rọ̀ ìlú tàbí fún ìdáàbòbò àláfíà àti ètò ọmọnìyàn.

Wọ́n dá àjọ yî silẹ̀ ní ọjọ́ kọkànlá, oṣù kejìlá, ọduń 1946 (11, December 1946). Àjọ yî tí a ń pè ní UNICEF jẹ́ àjọ kan tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ ní Orílẹ̀ èdè igba ó dín mẹ́wàá (190) láti máa dáàbò bo ètò àwon ọmọdé àti àwọn obìnrin ọlómọ tí ìparun Ogun àgbáyé ẹlẹ́ẹ̀kejí (World war II) deba.[1] Ní ọdún 1950, UNICEF fi àfikún sí ìrànlọ́wọ́ wọn, wọ́n sì sun dé ọ̀dọ̀ àwọn ará ìlú tí ìdàgbàsókè ṣẹ̀ṣẹ̀ ń débá. Ní Ọdún 1953, àwọn àjọ ìṣọ̀kan àgbáyé (United Nations) wá gba UNICEF wọlé làti máa ṣe ìrànlọ́wọ́ lábẹ́ ìjoba.[2]

Kì ni Isẹ́ UNICEF.

[àtúnṣe |àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìmójútó aàláfià àti ounjẹ: Wọ́n ṣètò àwọn abẹ́rẹ́ àjẹ-sàra, oúnjẹ tó da, wọ́n sì ń dínà àtànkálẹ̀ àrùn.

Ìpèsè Omi tío mọ: wọ́n ń ṣiṣẹ́ lórí lílékún ìpèsè omi tómọ́ tío sì dára fún ìlò.

Ètò Ẹ̀kó: Ṣíṣe àtìlẹyìn fún ẹ̀kọ́ àwọn ọmọdé.

Àbò: Wọ́n ń dá àbò bo àwọn ọmọdé kúrò nínú ìjànbá àti ìtànjẹ

Ìràlọ́wọ́ ní ásíkó pàjáwìrì: Wọ́n á màa ṣe ìrànlọ́wọ́ àwọn ará ìlú ní ìgbà ìdààmú.[3]

Wiwọle Owo fun Ise wọn.

[àtúnṣe |àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

UNICEF ò ní ẹ̀tọ́ nínú owó ìjoba àgbáyé, ṣùgbọ́n àwọn ẹ̀bùn láti ọwọ́ àwọn ènìyàn, ìjọba, àwọn àjọ àjùmọ̀ni tàbí àwọn àjọ aládàní-in ni wọ́n fi ń ṣiṣẹ́.[4]

Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí.

Ẹ lefẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ látifẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ.

Itokasi

[àtúnṣe |àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Search Wikimedia CommonsWikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́:UNICEF
  1. United Nations. (n.d.).UNICEF | United Nations. https://www.un.org/en/ccoi/unicef-united-nations-childrens-fund
  2. United Nations. (n.d.).UNICEF | United Nations. https://www.un.org/en/ccoi/unicef-united-nations-childrens-fund
  3. Google Search. (n.d.-b). https://www.google.com/search?client=opera&q=UNICEF&sourceid=opera&ie=UTF-8&oe=UTF-8
  4. Google Search. (n.d.-c). https://www.google.com/search?client=opera&q=UNICEF&sourceid=opera&ie=UTF-8&oe=UTF-8
Àwọn àgbájọáwọn ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn akáríayé àtiàwọn agbéró
International
institutions
Regional
bodies
Multi-lateral
bodies
MajorNGOs
1901–1925

Dunant /Passy (1901) ·Ducommun /Gobat (1902) ·Cremer (1903) ·IDI (1904) ·Suttner (1905) ·Roosevelt (1906) ·Moneta /Renault (1907) ·Arnoldson /Bajer (1908) ·Beernaert /Estournelles de Constant (1909) ·IPB (1910) ·Asser /Fried (1911) ·Root (1912) ·La Fontaine (1913) ·International Committee of the Red Cross (1917) ·Wilson (1919) ·Bourgeois (1920) ·Branting /Lange (1921) ·Nansen (1922) ·Chamberlain /Dawes (1925)

1926–1950

Briand /Stresemann (1926) ·Buisson /Quidde (1927) ·Kellogg (1929) ·Söderblom (1930) ·Addams /Butler (1931) ·Angell (1933) ·Henderson (1934) ·Ossietzky (1935) ·Lamas (1936) ·Cecil (1937) ·Nansen Office (1938) ·International Committee of the Red Cross (1944) ·Hull (1945) ·Balch /Mott (1946) ·QPSW /AFSC (1947) ·Boyd Orr (1949) ·Bunche (1950)

1951–1975

Jouhaux (1951) ·Schweitzer (1952) ·Marshall (1953) ·UNHCR (1954) ·Pearson (1957) ·Pire (1958) ·NoelBaker (1959) ·Lutuli (1960) ·Hammarskjöld (1961) ·Pauling (1962) ·International Committee of the Red Cross /League of Red Cross Societies (1963) ·King (1964) ·UNICEF (1965) ·Cassin (1968) ·ILO (1969) ·Borlaug (1970) ·Brandt (1971) ·Kissinger /Le (1973) ·MacBride /Sato (1974) ·Sakharov (1975)

1976–2000

B.Williams /Corrigan (1976) ·AI (1977) ·Sadat /Begin (1978) ·Mother Teresa (1979) ·Esquivel (1980) ·UNHCR (1981) ·Myrdal /García Robles (1982) ·Wałęsa (1983) ·Tutu (1984) ·IPPNW (1985) ·Wiesel (1986) ·Arias (1987) ·UN Peacekeeping Forces (1988) ·Dalai Lama (1989) ·Gorbachev (1990) ·Suu Kyi (1991) ·Menchú (1992) ·Mandela /de Klerk (1993) ·Arafat /Peres /Rabin (1994) ·Pugwash Conferences /Rotblat (1995) ·Belo /Ramos-Horta (1996) ·ICBL /J.Williams (1997) ·Hume /Trimble (1998) ·MSF (1999) ·Kim (2000)

2001–dòní

UN /Annan (2001) ·Carter (2002) ·Ebadi(2003) ·Maathai (2004) ·IAEA /ElBaradei (2005) ·Yunus /Grameen Bank (2006) ·Gore /IPCC (2007) ·Ahtisaari (2008) ·Obama (2009) ·Liu (2010) ·Sirleaf /Gbowee /Karman (2011) ·European Union (2012) ·Àgbájọ fún Ìdènà àwọn Ohun Ìjagun Ògùn Olóró (2013)

Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/w/index.php?title=UNICEF&oldid=606921"
Ẹ̀ka:
Ẹ̀ka bíbòmọ́lẹ̀:

[8]ページ先頭

©2009-2026 Movatter.jp