Simu Liu
Àwọn irinṣẹ́
Àpapọ̀
Ìtẹ́síìwé/ìkójáde
Ní àkànṣe iṣẹ́ míràn
Simu Liu | |||||||||||||||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
![]() Liu ní ọdún 2019 | |||||||||||||||||||||
Orúkọ àbísọ | 刘思慕 | ||||||||||||||||||||
Ọjọ́ìbí | 19 Oṣù Kẹrin 1989 (1989-04-19) (ọmọ ọdún 35) Harbin, Heilongjiang, China | ||||||||||||||||||||
Orílẹ̀-èdè | Canadian[1] | ||||||||||||||||||||
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Western Ontario (HBA) | ||||||||||||||||||||
Iṣẹ́ |
| ||||||||||||||||||||
Ìgbà iṣẹ́ | 2012–present | ||||||||||||||||||||
Awards | Full list | ||||||||||||||||||||
|
Simu Liu (/ˈsiːmuːˈliːjuː/SEE-moo-_-LEE-yoo;[2]Àdàkọ:Zh; tí a bí ní ọjọ́ kandínlógún oṣù Kerin ọdún 1989) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Kanada. Ó gbajúmọ̀ fún kíkọ́ ipaShang-Chi nínú fíìmùMarvel Cinematic Universe,Shang-Chi and the Legend of the Ten Rings tí ó jáde ní ọdún 2021. Ó tún kó ipa gẹ́gẹ́ bi Jung Kim nínú fíìmùCBC TelevisionKim's Convenience[3] ó sì gba àmì-ẹ̀yẹACTRA Award àtiCanadian Screen Awards fún ipa rẹ̀ nínúBlood and Water.[4]
Ní ọdún 2022, Liu ko ìwéWe Were Dreamers,[5]Time sì pè é ní ará àwọn òṣèré ọgọ́rùn-ún tí ó gbajúmọ̀ jùlọ ní àgbáyé.[6]