Movatterモバイル変換


[0]ホーム

URL:


Jump to content
Wikipedia
Ṣe àwáàrí

Radio Lagos

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Radio Lagos
CityÈkó
Broadcast areaÌpínlẹ̀ Èkó
Frequency107.5MHzFM
Language(s)Èdè ìbílẹ̀ abínibí ati èdè Gẹ̀ẹ́sì
Transmitter coordinates6°37′10.767″N3°21′12.719″E / 6.61965750°N 3.35353306°E /6.61965750; 3.35353306Coordinates:6°37′10.767″N3°21′12.719″E / 6.61965750°N 3.35353306°E /6.61965750; 3.35353306
OwnerLagos State Radio Corporation

Radio Lagos 107.5 FM tí a tún Mo sí (Tiwa n' Tiwa) ni ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní pẹrẹu ní ọdún 1977 ni ó jẹ́ ẹ̀ka tiNigerian Broadcasting Corporation. Ilé-iṣẹ́ asọ̀rọ̀mágbèsì yí jẹ́ ilé-iṣẹ́ ìròyìn àkọ́kọ́ tí yóò jẹ́ ti Ìpínlẹ̀ lórí ìkanìFM.

Ilé-iṣẹ́ asọ̀rọ̀mágbésì yí ń gbòhùn sáfẹ́fẹ́ lórí ìkànì A.M méjì (990 kHz.303mtrs àti 918 kHz.327mtrs) tẹ́lẹ̀. Látàrí ìṣèwádí ọ̀nà ọ̀tun láti lè ma kàn sí ọ̀gọ̀rọ̀ènìyàn ni ó bí ojú-òpó Radio Lagos tí ó wà ní orí ìkànì107.5 FM (Tiwa n'Tiwa) lábẹ́ àṣẹ àti ìdarí ilé-iṣẹ́ Lagos State Radio Service ní ọdún 2001.

Ilé-iṣẹ́ asọ̀rọ̀mágbèsì Radio Lagos ni ó kọ́kọ́ jẹ́ ilé-iṣẹ́ agbóhùn-sáfẹ́fẹ́ tí ó ń lo èdèYorùbá àti èdèÈgùn láti fi gbóhùn -sáfẹ́fẹ́ tí wọ́n sì ń lo ìdá méjì péré nínú ìdá ọgórùn ún èdè Gẹ̀ẹ́sì láti fi sọ ìròyìn. Àwọn tí ilé-iṣẹ́ rédíò yí fi sọ́kàn jùlọ láti jẹ́ olùgbọ́ wọn ni àwọn ọmọYorùbá nílé àti kókó.[1]

Ẹ tún lè wo

[àtúnṣe |àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn itọ́kasí

[àtúnṣe |àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Haris Aslam (20 November 2014)."Radio Lagos 107.5 Online".RadioAfrican. Archived fromthe original on 1 October 2020. Retrieved13 March 2021. 

Àwọn ìjásóde

[àtúnṣe |àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àdàkọ:Lagos


Àdàkọ:Africa-radio-station-stubÀdàkọ:Lagos-stub

Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/w/index.php?title=Radio_Lagos&oldid=578147"
Àwọn ẹ̀ka:

[8]ページ先頭

©2009-2025 Movatter.jp