Movatterモバイル変換


[0]ホーム

URL:


Jump to content
Wikipedia
Ṣe àwáàrí

Rómù Olómìnira

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Official name (as on coins):
Roma

after ca. 100 BC:
Senatus Populusque Romanus
("The Senate and People of Rome")
Àwọn Alàgbà àti àwọn Èniyàn ìlú Rómù


509 BC–27 BC

SPQR

Location of Roman Republic
Roman provinces on the eve of the assassination ofJulius Caesar, c. 44 BC
CapitalRome
Language(s)Latin,Greek
ReligionRoman polytheism
GovernmentRepublic
Consul
 -509508 BCLucius Junius Brutus,Lucius Tarquinius Collatinus
 -27 BCGaius Julius Caesar Octavianus,Marcus Vipsanius Agrippa
LegislatureRoman assemblies
Historical eraClassical antiquity
 - Rape ofLucretia509 BC
 - Caesar proclaimed perpetual dictator44 BC
 - Battle of Actium2 October 31 BC
 - Octavian proclaimedAugustus16 January, 27 BC
Area
 - 326 BC[1]10,000 km2(3,861 sq mi)
 - 200 BC[1]360,000 km2(138,997 sq mi)
 - 146 BC[1]800,000 km2(308,882 sq mi)
 - 100 BC[1]1,200,000 km2(463,323 sq mi)
 - 50 BC[1]1,950,000 km2(752,899 sq mi)

Orílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn ará Rómù (Latini: Res publica Romanorum) ni a n pe igba itan Romu ti awon ara Romu le oba ikeyin won kuro lori ite lati sepilese oselu. Igba oselu tabi igba olominira bere pelu iwolulo oba tokeyin ara Etruski, eyun Tarkuinu Onigberaga (Tarquinius Superbus) ni 509 kJ o si dopin pelu iboriOktabiani loriMarku Antoni niIja Aktiomu ni 31 kJ.



Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí.

Ẹ lefẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ látifẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ.

Itokasi

[àtúnṣe |àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/w/index.php?title=Rómù_Olómìnira&oldid=563077"
Àwọn ẹ̀ka:
Ẹ̀ka bíbòmọ́lẹ̀:

[8]ページ先頭

©2009-2026 Movatter.jp