Movatterモバイル変換


[0]ホーム

URL:


Jump to content
Wikipedia
Ṣe àwáàrí

Plánẹ́tì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àwọn pílánẹ́ẹ̀tì tó wà nínú àgbájọ oòrùn

Pílánẹ́tì gẹ́gẹ́ bí iẸgbẹ́ìrẹ́pọ̀ ìmọ̀ Òfurufú Káàkiriayé (IAU) ṣe ṣè'tumọ̀ rẹ̀ jẹ́ ohun òkè-ọrùn tí ó ń yí ìrànwọ́ ká tàbí aloku ọ̀run tí tíwúwosí rẹ̀ jẹ́ kí ó rí róbótó, tí kò tóbi púpọ̀ látiyíyọ́ ìgbónáinúikùn (anthothermonuclear fusion) láàyè nínú rẹ̀, tí ó sì ti gba àwọn oríṣiríṣi ìdènà kúra cartele dé santata lọ́nà tí ó ń gbà kọjá.

Àwọn Pílánẹ́tì tí ó wà nínú Ètò Òòrùn

[àtúnṣe |àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Gẹ́gẹ́ bí (IAU) ṣe sọ, pílánẹ́tì mẹ́jọ ni wọ́n wà nínúètò òòrùn. Àwọn nìwọ̀nyìí bí wọ́n ṣe ń jìnnà síÒòrùn:

  1. (☿)Mẹ́rkúríù
  2. (♀)Àgùàlà
  3. (🜨)Ilẹ̀-ayé
  4. (♂)Mársì
  5. (♃)Júpítérì
  6. (♄)Sátúrnù
  7. (♅)Úránù
  8. (♆)Nẹ́ptúnù
  1. ☿Mercury
  2. ♀Venus
  3. 🜨Earth
  4. ♂Mars
  5. ♃Jupiter
  6. ♄Saturn
  7. ♅Uranus
  8. ♆Neptune


Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí.

Ẹ lefẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ látifẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ.

Itokasi

[àtúnṣe |àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
    Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/w/index.php?title=Plánẹ́tì&oldid=592410"
    Àwọn ẹ̀ka:
    Ẹ̀ka bíbòmọ́lẹ̀:

    [8]ページ先頭

    ©2009-2026 Movatter.jp