Orílẹ̀òmìnira Pọ́rtúgàl Portuguese Republic
República Portuguesa |
|---|
|
|
![Ibùdó ilẹ̀ Pọ́rtúgàl (dark green) – on the European continent (green & dark grey) – in the European Union (green) — [Legend]](/image.pl?url=https%3a%2f%2fyo.wikipedia.org%2f%2fupload.wikimedia.org%2fwikipedia%2fcommons%2fthumb%2fa%2fa0%2fEU-Portugal_with_islands_circled.svg%2f330px-EU-Portugal_with_islands_circled.svg.png&f=jpg&w=240) |
Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ | Lisbon |
|---|
| Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Portuguese |
|---|
| Lílò regional languages | Mirandese1 |
|---|
| Àwọn ẹ̀yà ènìyàn (2007) | 96.87%Portuguese and 3.13% legal immigrants (Cape Verdeans,Brazilians,Ukrainians,Angolans, etc.)[1] |
|---|
| Orúkọ aráàlú | Portuguese |
|---|
| Ìjọba | Orílẹ̀òmìnira oníléaṣòfin |
|---|
|
| Marcelo Rebelo de Sousa |
|---|
| António Costa |
|---|
| Eduardo Ferro Rodrigues |
|---|
|
| Formation Conventional date for Independence is1139 |
|---|
|
| 868 |
|---|
| 1095 |
|---|
| 24 June 1128 |
|---|
| 25 July 1139 |
|---|
| 5 October 1143 |
|---|
| 23 May 1179 |
|---|
| 1 December 1640 |
|---|
| 13 February 1668 |
|---|
| 5 October 1910 |
|---|
| 25 April 1974 |
|---|
|
| Ìtóbi |
|---|
• Total | 92,090 km2 (35,560 sq mi) (110th) |
|---|
• Omi (%) | 0.5 |
|---|
| Alábùgbé |
|---|
• 2011 estimate | 10,647,763[2] (77th) |
|---|
• 2011 census | 10,555,853[3] |
|---|
• Ìdìmọ́ra | 115/km2 (297.8/sq mi) (96th) |
|---|
| GDP (PPP) | 2010 estimate |
|---|
• Total | $247.037 billion[4] |
|---|
• Per capita | $23,222[4] |
|---|
| GDP (nominal) | 2010 estimate |
|---|
• Total | $229.336 billion[4] |
|---|
• Per capita | $21,558[4] |
|---|
| Gini (1997) | 38.5[5] Error: Invalid Gini value |
|---|
| HDI (2010) | ▲ 0.795[6] Error: Invalid HDI value · 40th |
|---|
| Owóníná | Euro (€)2 (EUR) |
|---|
| Ibi àkókò | UTC0 (WET3) |
|---|
| UTC+1 (WEST) |
|---|
| Irú ọjọ́ọdún | dd-mm-yyyy, yyyy-mm-dd, yyyy/mm/dd |
|---|
| Ojúọ̀nà ọkọ́ | right |
|---|
| Àmì tẹlifóònù | 351 |
|---|
| Internet TLD | .pt4 |
|---|
|
Pọ́rtúgàl (
i/ˈpɔrtʃʉɡəl/Pọrtugí:Portugal), lonibise biOrileominira Portugal (Pọrtugí:República Portuguesa[8]), je orile-ede to budo si apaguusuiwoorunEurope loriPenisula Iberia. Portugal ni orile-ede to sunmo apa iwoorun julo ni Europe, be sini o ni bode moOkun Atlantiki ni iwoorun ati ni guusu, bode moSpain ni ariwa ati ilaorun. Awonisujo erekusu inu Atlantiki, eyunAzores atiMadeira je ara Portugal. Orile-ede yi gba oruko re lati ibi oruko ilu re totobijulo keji,Porto, ti oruko Latini re jePortus Cale.
Ori ile to wa ninu bode Orileominira Portugal loni ti je titedo leralera lati awonigba iwaju itanakole: latowo awonGallaeci ati awonLusitanians, o bo si inuIleobaluaye Romu be sini awon eniyan elede Jemani biSuevi ati awonVisigoths na tedo sibe, ni orundun 8k awonMauri bori ibe. NigbaReconquista awon Elesin Kristi, Portugal seda ara re bi ileoba alominira, tori ni won se unpe biorile-ede-ajoba togbojulo ni Europe.[9]
Ni orudnun 15k ati 16k, ntoripe o lewajuIgba Iwari, Portugal diileobaluaye to nile kakiriAfrika,Asia,Oseania, atiGusu Amerika, lati di ikan ninu awon alagbara itokowo, oloselu ati ologun lagbaye. Ileobaluaye Portugal ni ileobaluaye akariaye akoko ninu itan,[10] ati eyi to pejulo ninu gbogbo awon obaluaye alamusin Europe. Sibesibe, ipo orile-ede ti je riresile gan titi to fi di orundun 19k, agaga leyinilominira ile Brasil, to je imusin totobijulo re.
- ↑Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref> tag; no text was provided for refs namedine.pt - ↑Pordata, "Base de Dados Portugal Contemporâneo". Accessed on March 7, 2011.
- ↑http://www.ine.pt/scripts/flex_v10/Main.html
- ↑4.04.14.24.3"Portugal". International Monetary Fund. Retrieved6 May 2011.
- ↑"Gini Index". World Bank. Retrieved2 March 2011.
- ↑"Human Development Report 2010"(PDF). United Nations. 2010. Retrieved5 November 2010.
- ↑The Euromosaic study, Mirandese in PortugalArchived 2007-03-13 at theWayback Machine., europa.eu –European Commission website. Retrieved January 2007.
- ↑(Potogí)Portal do Governo[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑Brian Jenkins, Spyros A. Sofos,"Nation and identity in contemporary Europe", p.145 Routledge, 1996,ISBN 0-415-12313-5
- ↑Melvin Eugene Page, Penny M. Sonnenburg, p. 481