Páálù[lower-alpha 1] (tí àwọn míràn mọ̀ síSaalu ara Tarsus;[lower-alpha 2],Páálù àpọ́sítélì[2] tàbíPáálù ẹni mímọ́,[3] jẹ́ ọ̀kan lára àwọn Àpọ́sítélì mejemu titun tí ó polongo iṣẹ́ ìránṣẹ́ Jesu Kristi.[4] Páálù wà lára àwọn ènìyàn nígbà ayé àwọn Àpọ́sítélì tí wón kà se pataki ní ìtàn.[3][5] Ó dá ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìjọ sílè ní Asia àtiEurope.[6]
Gégé bí ìwé májẹ̀mú tuntun ìṣe àwọn Àpọ́sítélì ṣe ṣàlàyé, Páálù je Farisí.[7] Ó sì kópa nínú sí isenunibinu ìjọba Róòmù sí àwọn Kristẹni àkọ́kọ́,[8] ní Jerúsálẹ́mù kí ó tó di pé ó di ẹni ìgbàlà.[note 1] Ìgbà di ẹ̀ lẹ́yìn ìgbà tí ó fi owó sí isekupa Stefani,[9] Páálù ń rìn ìrìn àjò lọ sí Damásíkù láti wá àwọn Kristẹni àti láti "kó wọn ní ìdè wá sí Jerúsálẹ́mù"(ESV).[10] Ní àárín ọjọ́, imole ńlá tàn sí Paalu àti àwọn tó yi ká, èyí mú kí ó ṣubú, tí Jesu sì bẹ̀rẹ̀ lọ́wọ́ rẹ̀ wí pé "kí ló dé tí ó fi ń ṣe inúnibíni sí mi".[11][12]
Ojú Paalu kò láti ríran,[13] à si pàṣẹ fun láti wo ìlú náà. Iriran Paalu padà bò sípò lẹ́yìn ìjọ mẹ́ta nígbà tí Ananíà ará Damásíkù gbàdúrà fun. Léyìn n kan wò yín, wọ́n ṣe itebomi fún Paalu, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí polongo pé Jesu ni olùgbàlà àti ọmọ Olorun.[14] Bi idasi-meji ìwé ìṣe àwọn Àpọ́sítélì sọ̀rọ̀ nípa ìgbé ayé Paalu.
Àwọn míràn gbàgbọ́ pé Paalu ni ó ko mẹ́rìnlá nínú àwọn ìwé metadinlogbon tiMájẹ̀mú Láéláé.[15] Bí ó ti lè jẹ́ wípé àríyànjiyàn wà láàrin àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n lórí bóyá òhun ló kọ àwọn míràn nínú àwọn ìwé yìí àbí òun kọ́.
- ↑1.01.1Harris, p. 411
- ↑Brown 1997, p. 442.
- ↑3.03.1Sanders 2019.
- ↑Powell 2009.
- ↑Dunn 2001, Ch 32.
- ↑Rhoads 1996, p. 39.
- ↑Acts 26:5 ESV
- ↑Dunn 2009, pp. 345–346.
- ↑Acts 8:1 ESV
- ↑Acts 9:2 ESV
- ↑Acts 26:13–14 ESV
- ↑Acts 22:7–9 ESV
- ↑Acts 22:11 ESV
- ↑Acts 9:3–22 ESV
- ↑Brown 1997, p. 407.
- ↑Látìnì:Paulus;Èdè Grííkì Ayéijọ́un: Παῦλος;Àdàkọ:Lang-cop;Àdàkọ:Lang-hbo
- ↑Àdàkọ:Lang-hbo;Lárúbáwá:بولس الطرسوسي;Èdè Grííkì Ayéijọ́un: Σαῦλος Ταρσεύς [Saũlos Tarseús]error: [undefined]error: {{lang}}: no text (help): text has italic markup (help);Àdàkọ:Lang-tr;Látìnì:Paulus Tarsensis
Àṣìṣe ìtọ́kasí:<ref> tags exist for a group named "note", but no corresponding<references group="note"/> tag was found