Movatterモバイル変換


[0]ホーム

URL:


Jump to content
Wikipedia
Ṣe àwáàrí

Owó-ẹ̀yìn

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
"Corrupt solicitation, acceptance, or transfer of value in exchange for official action."Àdàkọ:SHORTDESC:"Corrupt solicitation, acceptance, or transfer of value in exchange for official action."
Giving money illegally or unethically to influence a person's behavior is a form of bribery.

Owó-ẹ̀yìn tàbíẸ̀gúnjẹ ni gbígba owó tàbí ẹ̀bùn mìíràn lọ́nà àìtó láti ṣẹ̀gbẹ̀ fúnni fún èyíkéyìí àǹfàní. Ó jẹ́ ọ̀kan lára ìwà àjẹbánu tó burú jáì. Àwọn ọ̀gá ilé-iṣẹ́, àwọn olórí, Aláṣẹ tàbí àwọn olóṣèlú ni aje ìwà ìbàjẹ́ yìí sáàbà máa ń sẹ́ lórí jùlọ. Àwọn àwọn Adájọ́, Ọ̀lọ́pàá àti àwọn agbófinró mìíràn a máa gba Ẹ̀gúnjẹ láti ṣẹ̀gbẹ̀ fún ọ̀daràn tàbí láti gbẹ́bi fún aláre. Owó-ẹ̀yìn, tí a tún lè pè ní owó-àbẹ̀tẹ́lẹ̀ tún máa ń wáyé àwọn ilé ẹ̀kọ́. Àwọn olùkọ́ mìíràn a máa Ẹ̀gúnjẹ láti fún akẹ́kọ̀ọ́ ní máàkì tàbí fún un ní èsì ìbéèrè ìdánwò.[1][2][3][4]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe |àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "What is BRIBERY? definition of BRIBERY (Black's Law Dictionary)".The Law Dictionary. 2011-11-04. Retrieved2020-01-22. 
  2. "Bribery".LII / Legal Information Institute. 2016-07-25. Retrieved2020-01-22. 
  3. "Don't Pay for the Misdeeds of Others: Intro to Avoiding Foreign Third-Party FCPA Liability".Perkins Coie. Archived fromthe original on 2014-03-16. Retrieved2020-01-22. 
  4. "African corruption 'on the wane'".BBC NEWS. 2007-07-10. Retrieved2020-01-22. 


Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí.

Ẹ lefẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ látifẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ.

Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/w/index.php?title=Owó-ẹ̀yìn&oldid=590160"
Ẹ̀ka:
Áwọn ẹ̀ka bíbòmọ́lẹ̀:

[8]ページ先頭

©2009-2026 Movatter.jp