Monalisa Chinda
Àwọn irinṣẹ́
Àpapọ̀
Ìtẹ́síìwé/ìkójáde
Ní àkànṣe iṣẹ́ míràn
Monalisa Chinda | |
---|---|
![]() Monalisa Chinda ati Mr Ibu níbi àmì-ẹ̀yẹ ti Magic Viewers Choice ti ilẹ̀ Áfíríkà ni ọdún 2014. | |
Ọjọ́ìbí | Monalisa Chinda 13 Oṣù Kẹ̀sán 1974 (1974-09-13) (ọmọ ọdún 50) Port Harcourt, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | ỌmọNàìjíríà |
Iṣẹ́ | Òṣèrébìnrin, olóòtú sinimá àgbéléwò, olúgbóhùnsáfẹ́fẹ́ |
Ìgbà iṣẹ́ | ọdún 1996 títí di àkókò yìí |
Monalisa Chinda tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹsàn-án ọdún 1974 (13th September 1974)[1] jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin àti olóòtú sinimá àgbéléwò, ọmọ bíbí orílẹ̀ èdèNàìjíríà. Ó jẹ́ olóòtú ètò orí tẹlifíṣàn àti gbajúmọ̀ olúgbóhùnsáfẹ́fẹ́.[2]