Lafia
Àwọn irinṣẹ́
Àpapọ̀
Ìtẹ́síìwé/ìkójáde
Ní àkànṣe iṣẹ́ míràn
Lafia Lafiyan | |
---|---|
LGA and town | |
![]() | |
Nickname(s): Lafia Garin Madidi | |
Coordinates:8°29′30″N8°31′0″E / 8.49167°N 8.51667°E /8.49167; 8.51667 | |
Country | ![]() |
State | Nasarawa State |
Government | |
• Emir | Hon. Justice Sidi Bage Muhammad I JSC Rtd. |
• LGAChairman | Alh. Aminu Mu'azu Maifata |
Population (2006) | |
• Total | 330,712 |
[1] | |
Time zone | UTC1 (WAT) |
Climate | Aw |
Lafia jẹ́ ìlú kan ní àárín gbùngbùn Gúúsù ilẹ̀Nàìjíríà. Òun ni olú-ìlúÌpínlẹ̀ Nasarawa ó sì ní àwọn olùgbé tí ó tó 330,712 ènìyàn gẹ́gẹ́ bí ètò ìkànìyàn ọdún 2006 ní Nàìjíríà sọ.[1] Òun ni ìlú tí ó tóbi jù ní ìpínlẹ̀ Nasarawa.
Àwọn míràn mo ìlú Lafia sí Lafian bare-Bari.Muhammadu Dunama ni ó dá ìlú náà kalẹ̀ ní ọdún 17k.
![]() | Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ lefẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ látifẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |