Kim Fields
Àwọn irinṣẹ́
Àpapọ̀
Ìtẹ́síìwé/ìkójáde
Ní àkànṣe iṣẹ́ míràn
Kim Fields | |
---|---|
![]() Fields in 2019 | |
Ọjọ́ìbí | Kim Victoria Fields 12 Oṣù Kàrún 1969 (1969-05-12) (ọmọ ọdún 55) New York City, New York, U.S. |
Orúkọ míràn | Kim Fields Freeman |
Ẹ̀kọ́ | Pepperdine University |
Iṣẹ́ | Actress, director |
Ìgbà iṣẹ́ | 1977–present |
Gbajúmọ̀ fún | The Facts of Life,Living Single |
Olólùfẹ́ | Johnathon Franklin Freeman (m. 1995–2001) Christopher Morgan (m. 2007) |
Àwọn ọmọ | 2 |
Parent(s) | Chip Fields (mother) |
Àwọn olùbátan | Alexis Fields (sister) |
Kim Victoria Fields (ọjọ́ìbí May 12, 1969) ni òṣeré àti olúdarí ètò tẹlifísàn ará Amẹ́ríkà. Fields gbajúmọ̀ fún ìseré rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi Dorothy "Tootie" Ramsey nínúeré aláwàdà ilé-iṣẹ́ tẹlifísànNBCThe Facts of Life (1979–1988), àti gẹ́gẹ́ bíi Regine Hunter nínú eré aláwàdà ilé-iṣẹ́ tẹlifísànFox,Living Single (1993–1998). Fields ni ọmọChip Fields tí òhun náà jẹ̀ òṣeré àti olùdarí, àti ẹ̀gbọ́n Alexis Fields.