Movatterモバイル変換


[0]ホーム

URL:


Jump to content
Wikipedia
Ṣe àwáàrí

Kenya

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Orile-ede Olominira ile Kẹ́nyà
Republic of Kenya

Jamhuri ya Kenya(Swahili)
Motto: "Harambee"(Swahili)
"Let us all pull together"
Orin ìyìn: "Ee Mungu Nguvu Yetu"
(English:"O God of all creation")
Show globe
Show map of Africa
Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Nairobi
1°16′S36°48′E / 1.267°S 36.800°E /-1.267; 36.800
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba
National languageSwahili[1]
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn
(2019[2])
Ẹ̀sìn
(2019[2])
Àdàkọ:Ublist
Orúkọ aráàlúKenyan
ÌjọbaUnitarypresidentialconstitutionalrepublic
Uhuru Kenyatta
William Ruto
Kenneth Lusaka
Justin Muturi
David Maraga
Paul Kihara Kariuki
AṣòfinParliament
Senate
National Assembly
Independence
• from theUnited Kingdom
12 December 1963
• Republic declared
12 December 1964
Ìtóbi
• Total
580,367 km2 (224,081 sq mi)[3][4] (48th)
• Omi (%)
2.3
Alábùgbé
• 2019 census
47,564,296[5] (29th)
• Ìdìmọ́ra
78/km2 (202.0/sq mi) (124th)
GDP (PPP)2020 estimate
• Total
$206.532 billion[6]
• Per capita
$4,071[7]
GDP (nominal)2020 estimate
• Total
$109.116 billion[7]
• Per capita
$2,151[7]
Gini (2014)42.5[8]
medium · 48th
HDI (2018) 0.579[9]
medium · 147th
OwónínáKenyan shilling (KSH)
Ibi àkókòUTC+3 (EAT)
Irú ọjọ́ọdúndd/mm/yy (AD)
Ojúọ̀nà ọkọ́left
Àmì tẹlifóònù+254
Internet TLD.ke
[10] According to the CIA, estimates for this country explicitly take into account the effects of mortality because of AIDS; this can result in lower life expectancy, higher infant mortality and death rates, lower population and growth rates, and changes in the distribution of population by age and sex, than would otherwise be expected.

Kẹ́nyà tàbíOrile-ede Olominira ile Kẹ́nyà je orile-ede niÌlaòrùn Áfríkà. O dubule si ebaOkun India, niagedemeji aye, Kẹ́nyà ni bode moEthiópíà (ariwa),Sòmálíà (ariwailaorun),Tànsáníà (guusu),Ùgándà atiLake Victoria (iwoorun), ati Orile edeGúúsù Sudan (ariwaiwoorun). Oluilu re niNairobi. Awon onibugbe ibe ti po to 38 legbegberun.

Awon Igberiko, ibile ati awon ipinsi

[àtúnṣe |àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Provinces of Kẹ́nyà

Kenya pinsi awonigberiko 8 ti olori won n je Alakoso Igberiko (Aare lo n yan won). Awon igberiko wonyi (mkoa singularmikoa plural inSwahili) na tun je pinpin siawon ibile (wilaya). Awon ibile 69 lo wa. Awon ibile wonyi na tun je pipin siawon ipinsi 497 (taarafa). Awon ipinsi tu je pipin si 2,427awon ibudo 2,427 (mtaa) ati omo ibudo 6,612 (mtaa mdogo).[11]. Awon igberiko na niwonyi:

  1. Igberiko Aarin
  2. Igberiko Eti Okun
  3. Igberiko Apailaorun
  4. Igberiko Nairobi
  5. Igberiko Ariwa Apailaorun
  6. Igberiko Nyanza
  7. Igberiko Rift Valley
  8. Igberiko Apaiwoorun

Iye awon onibugbe awon ilu ninla

[àtúnṣe |àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
IluIye eniyan
Nairobi2 940 911
Mombasa707 400
Nakuru337 200
Kisumu273 400
Eldoret249 100
Nyeri213 000
Machakos179 500
Meru140 900



Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí.

Ẹ lefẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ látifẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ.


Itokasi

[àtúnṣe |àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. 1.01.1Constitution (2009) Art. 7 [National, official and other languages] "(1) The national language of the Republic is Swahili. (2) The official languages of the Republic are Swahili and English. (3) The State shall–-–- (a) promote and protect the diversity of language of the people of Kenya; and (b) promote the development and use of indigenous languages, Kenyan Sign language, Braille and other communication formats and technologies accessible to persons with disabilities."
  2. 2.02.1"2019 Kenya Population and Housing Census Volume IV: Distribution of Population by Socio-Economic Characteristics".Kenya National Bureau of Statistics. Retrieved24 March 2020. 
  3. "Demographic Yearbook – Table 3: Population by sex, rate of population increase, surface area and density"(PDF). United Nations Statistics Division. 2012. Retrieved4 September 2017. 
  4. "United Nations Statistics Division - Demographic and Social Statistics".unstats.un.org. 
  5. "2019 Kenya Population and Housing Census Results".Kenya National Bureau of Statistics. 4 November 2019. Retrieved15 November 2019. 
  6. "Report for Selected Countries and Subjects (valuation of Kenya GDP)". International Monetary Fund. 
  7. 7.07.17.2"World Economic Outlook Database, April 2019".IMF.org.International Monetary Fund. Retrieved15 June 2019. 
  8. "Human Development Report 2014"(PDF). United Nations. 2014. Retrieved26 July 2014. 
  9. "Human Development Report 2019"(PDF) (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì).United Nations Development Programme. 10 December 2019. Retrieved10 December 2019. 
  10. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid<ref> tag; no text was provided for refs namedcia
  11. Central Bureaus of Statistics (Kenya):Census cartography: The Kenyan Experience
Search Wikimedia CommonsWikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́:Kenya


Àwọnorílẹ̀-èdè apàṣẹ
Algeria ·Angola ·Benin ·Botswana ·Burkina Faso ·Burundi ·Cameroon ·Cape Verde ·Central African Republic ·Chad ·Comoros ·Democratic Republic of the Congo ·Republic of the Congo ·Côte d'Ivoire (Ivory Coast) ·Djibouti ·Egypt ·Equatorial Guinea ·Eritrea ·Ethiopia · France(Mayotte ·Réunion) ·Gabon ·The Gambia ·Ghana ·Guinea ·Guinea-Bissau · Italy(Pantelleria) ·Kenya ·Lesotho ·Liberia ·Libya ·Madagascar ·Màláwì ·Mali ·Mauritania ·Mauritius ·Morocco ·Mozambique ·Namibia ·Niger ·Nigeria · Portugal(Madeira) ·Rùwándà ·São Tomé and Príncipe ·Senegal ·Seychelles ·Sierra Leone ·Somalia ·South Africa ·South Sudan(from 9 July 2011) · Spain(Canary Islands ·Ceuta ·Melilla ·Plazas de soberanía) ·Sudan ·Swaziland ·Togo ·Tanzania ·Tunisia ·Uganda · Yemen(Socotra) ·Zambia ·Zimbabwe
States with
limited recognition
Dependencies
Unclear sovereignty
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/w/index.php?title=Kenya&oldid=582782"
Àwọn ẹ̀ka:
Ẹ̀ka bíbòmọ́lẹ̀:

[8]ページ先頭

©2009-2025 Movatter.jp