Nilanjana Sudeshna "Jhumpa" Lahiri[1] (tí wọ́n bí ní July 11, 1967) jẹ́ òǹkọ̀wé ti Indian àti American, tí ó gbajúmọ̀ fún àwọn ìtàn kékeré rẹ̀, ìwé ìtàn-àròsọ àti àròkọ rẹ̀ ní èdè Gẹ̀ẹ́sì àti ní èdèItaly.
À̀tòjọ ìtàn kékeré rẹ̀ niInterpreter of Maladies (1999) tó gba ẹ̀bùn Pulitzer Prize for Fiction àti ẹ̀bùn PEN/Hemingway Award, ìwé ìtàn-àròsọ rẹ̀,The Namesake (2003), ni ó fàyọ nínú fíìmù àgbéléwòThe Namesake.
Wọ́n bí Lahiri sí ìlú London, ó sì jẹ́ ọmọbìnrin ti àwọn aráIndia tó sí lọ síWest Bengal. Ìdílé rẹ̀ kó lọ síUnited States nígbà tó wà ní ọmọ-ọdún mẹ́ra; Lahiri máa ń rí ara rẹ̀ bí i ará America, ó sì máa ń sọ pé, "Wọn ò bí mi síbi àmọ́ ó ṣe é ṣe kó jẹ́ bẹ́ẹ̀."[2] Lahiri dàgbà sí Kingston, ní Rhode Island, níbi tí bàbá rẹ̀, ìyẹn Amar Lahiri ti ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí i librarian ní University of Rhode Island;[2] ìwé "The Third and Final Continent", ìtàn tó paríInterpreter of Maladies, jẹ́ èyí tó kọ nípa bàbá rẹ̀.[3] Ìyá Lahiri fẹ́ kí àwọn ọmọ òun dàgbà sí mímọ àṣà Bengali, àwọn mọ̀lẹ́bí rẹ̀ sì máa ń wá wò wọ́n dáadáa ní Calcutta.[4]
1993 – TransAtlantic Award from the Henfield Foundation
1999 – O. Henry Award for short story "Interpreter of Maladies"
1999 – PEN/Hemingway Award (Best Fiction Debut of the Year) for "Interpreter of Maladies"
1999 – "Interpreter of Maladies" selected as one ofBest American Short Stories
2000 – Addison Metcalf Award from the American Academy of Arts and Letters
2000 – "The Third and Final Continent" selected as one ofBest American Short Stories
2000 –The New Yorker Best Debut of the Year for "Interpreter of Maladies"
2000 – Pulitzer Prize for Fiction for her debut "Interpreter of Maladies"
2000 – James Beard Foundation's M.F.K. Fisher Distinguished Writing Award for "Indian Takeout" inFood & Wine Magazine
2002 – Guggenheim Fellowship
2002 – "Nobody's Business" selected as one ofBest American Short Stories
2008 – Frank O'Connor International Short Story Award for "Unaccustomed Earth"
2009 – Asian American Literary Award for "Unaccustomed Earth"
2009 – Premio Gregor von Rezzori for foreign fiction translated into Italian for "Unaccustomed Earth" ("Una nuova terra"), translated by Federica Oddera (Guanda)
2014 – DSC Prize for South Asian Literature forThe Lowland[5]
2023 – Honorary Doctorate from The American University of Rome in recognition of her extraordinary contribution to literature in English and Italian.[7]