Movatterモバイル変換


[0]ホーム

URL:


Jump to content
Wikipedia
Ṣe àwáàrí

Johannes Hans Daniel Jensen

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe látiJ. Hans D. Jensen)
Johannes Hans Daniel Jensen
Ìbí25 Osu Kefa, 1907
Hamburg
Aláìsí11 Osu Keji, 1973
Heidelberg
Ọmọ orílẹ̀-èdèaraJemani
Pápáfisiksi
Ibi ẹ̀kọ́Yunifasiti ilu Hamburg
Doctoral advisorWilhelm Lenz
Doctoral studentsHans-Arwed Weidenmüller
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síEbun Nobel ninu Fisiksi (1963)

Johannes Hans Daniel Jensen (June 25, 1907 niHamburg – February 11, 1973 niHeidelberg) je araJemani to je onimo fisiksi inuatomu. Nigba Ogun Agbaye Keji, o sise lori ise okun inuatomu fun Jemani, to unje Agbo Uraniom, ninu ibi to ti se afikun pataki si ipinya awon isotopu uraniom. Leyin ti ogun pari, o sise bi ojogbon ni Yunifasiti ilu Heidelberg. O tun je ojogbon alejo ni Yunifasiti Wisconsin–Madison, the Institute for Advanced Study, Indiana University, ati the California Institute of Technology. Jensen pinEbun Nobel ninu Fisiksi odun 1963 peluMaria Göppert-Mayer fun aba won funafijuwe igbaeyin inuatomu.


Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí.

Ẹ lefẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ látifẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ.

Itokasi

[àtúnṣe |àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
ÀwọnẸlẹ́bùn Nobel nínúFísíksì (1951–1975)
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/w/index.php?title=Johannes_Hans_Daniel_Jensen&oldid=515715"
Àwọn ẹ̀ka:
Ẹ̀ka bíbòmọ́lẹ̀:

[8]ページ先頭

©2009-2025 Movatter.jp