Isaac Newton (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrin oṣù kìíní ọdún 1643 - ọjọ́ kọkànlélọ̀gbọ̀n oṣù kẹta 1727) jẹ́onímọ̀ sáyẹ́nsì ọmọ orílẹ̀-èdèGẹ̀gẹ̀ẹ́sì. Ó jẹ́ amọ̀ye ninu ẹ̀kọ́ ìsirò, awòràwọ̀, ẹ̀sìn àti ònkòwé. Ní ìgbà ayé rẹ̀, wọ́ń mọ si amọ̀ye ohun gbogbo.Látìnì:Philosophiæ Naturalis Principia Mathematica, ìwé ti ó kọ ní ọdún 1687 jẹ́ ìpìlẹ̀ fun ìsisẹ́ẹ̀ro ayébáyé (nínu ẹkọ́ọ físíìsì). Ìwé yìí wà nípa òfin ìsirò lóri ìmọ̀ye ìṣẹ̀dá, ó sìm jẹ́ awọn ofin akọ́kọ́.
Oga ti ile-ijosin ti so pé ni asiko ti iku tiAlàgbà Newton pé "Iseda ati ofin ti iseda ti dubule pamo ninu ale, Olúwa-Ọlọrun ti so pe, e je ki Newton je láàyè! Ati ohun gbogbo ti wa sinu imolẹ."[7]
- ↑1.01.1During Newton's lifetime, two calendars were in use in Europe: theJulian or 'Old Style' in Britain and parts of northern Europe (Protestant) and eastern Europe, and theGregorian or 'New Style', in use in Roman Catholic Europe and elsewhere. At Newton's birth, Gregorian dates were ten days ahead of Julian dates: thus Newton was born on Christmas Day, 25 December 1642 by the Julian calendar, but on 4 January 1643 by the Gregorian. By the time he died, the difference between the calendars had increased to eleven days. Moreover, prior to the adoption of the Gregorian calendar in the UK in 1752, the English new year began (for legal and some other civil purposes) on 25 March ('Lady Day', i.e. the feast of the Annunciation: sometimes called 'Annunciation Style') rather than on 1 January (sometimes called 'Circumcision Style'). Unless otherwise noted, the remainder of the dates in this article follow the Julian Calendar.
- ↑Mordechai Feingold,Barrow, Isaac (1630–1677),Oxford Dictionary of National Biography,Oxford University Press, September 2004; online edn, May 2007; accessed 24 February 2009; explained further in Mordechai Feingold "Newton, Leibniz, and Barrow Too: An Attempt at a Reinterpretation";Isis, Vol. 84, No. 2 (June, 1993), pp. 310-338
- ↑Dictionary of Scientific Biography, Newton, Isaac, n.4
- ↑Gjersten, Derek (1986). The Newton Handbook. London: Routledge & Kegan Paul.
- ↑Westfall, Richard S. (1983) [1980]. "Never at Rest: A Biography of Isaac Newton. Cambridge: Cambridge University Press. pp. 530–1. ISBN 0521274354, 9780521274357.
- ↑Snobelen, Stephen D. (1999). "Isaac Newton, heretic: the strategies of a Nicodemite" (PDF). British Journal for the History of Science 32: 381–419. doi:10.1017/S0007087499003751. Archived fromthe original on 2013-10-07. https://web.archive.org/web/20131007005450/http://isaac-newton.org/heretic.pdf. Retrieved 2009-11-20.
- ↑https://www.americanscientist.org/article/and-all-was-light
|
|---|
| Base units | |
|---|
| Derived units | |
|---|
| See also | |
|---|