John Berners-Lee (Eleda ti Intaneeti)Amerika AriwaKomputa ati Intaneeti (Ayelujara)
Íńtánẹ́ẹ̀tì jẹ́ asopọ̀ bí ìtakùn àwọn ẹ̀rọ kọ̀m̀pútà káàkiri àgbáyé fún ìpàṣípààrọ̀ ìpolongo àti ìmọ̀. Níèdè Gẹ̀ẹ́sì ó wá láti orúkọinter - network, nítorí náà níèdè Yorùbá à ń pè níÍńtánẹ́ẹ̀tì.
Intaneeti tabi Ayelujara ran wa lowo lati se orisirisi ohun. Pelu Intaneeti awa le ri alaye, iroyin, ati sopo pelu gbogbo èniyàn ni ayika agbayé.
Bee ni, INtaneeti wa laaye nitori siseto (coding), pelu siseto Intaneeti wa laaye. Intaneeti je da pelu awon 1, 0. She ti mo be? Nikan pelu 1s ati 0s, Intaneeti wa laaye? Awa n pe be siseto.
Ko si èniyàn okan ti a ti da Intaneeti tabi ayelujara sugbon lapapo, orisirisi èniyàn ti da Intaneeti. Oruko won ni Alagba Timothy John Berners-Lee, Paul Baran (1926-2011), LAWRENCE ROBERTS (1937–2018), LEONARD KLEINROCK (1934–), Leonard KleinRock je laaye nissi, DONALD DAVIES (1924–2000), BOB KAHN (1938–) ati VINT CERF (1943–), PAUL MOCKAPETRIS (1948–) ati JON POSTEL (1943–98), ati orisirisi miiran. O ko ti je ise ti okunrin okan, sugbon ise ti orisirisi okunrin. Nissi, ayelujara ati Intaneeti tesiwaju lati dagba, da, mu gbọ́n ju, ati ran gbogbo èniyàn lowo. Bee ni, Intaneeti je wulo gidigan.
Oye Atowoda
Intaneeti ran awon omodé wa lati kiko ati kawe. Pelu intaneeti awa ni alaye ti o po ju, o je rorun lati wiwole ati o je ofe! Bee ni, awa ni ohun (audio), fidio ti awon iwe ko ni. Intaneeti je fafa, ati o le gba alaye ti o po ju awon iwe. E le fi kun alaye ailopin si ati ninu Intaneeti (ayelujara)!
Intaneeti ran wa lowo ni orisirisi ona. Intaneeti ran wa lowo lati kiko awon ohun titun, gbogbo èniyàn mo awon ohun ti sele ni awon ile yato. Intaneeti ran wa lowo lati soro pelu awon èniyàn ti awa feran ati nife. Awon aladuugbo wa, obi wa, ebi wa, ore wa, olutojueni wa, ati awon ti wa apa miiran ti agbayé! Ni Naijiria (Nigeria), Canada, Amerika, Ilu Faransé, ati miiran. Pelu Intaneeti awa le soro pelu awon èniyàn ti wa jina lati wa.
Intaneeti le asotele oju ojo. Ti awa ma ni ojo, o ma asotele e, ti awa ma ni iji lile, Intaneeti, o ma asotele e.
ChatGPT je roboti tabi Oye Atowoda ti awon èniyàn lo lati ri awon idahun fun awon ibeere won. ChatGPT ni oye sùgbon ko wa peye nigbagbogbo, e sora! Oye Atowo -
Scratch je aaye ayelujara fun awon omodé lati kiko bawo siseto. O je igbadun ati ajọṣepọ fun awon omodé. Bee ni Scratch wa ni awon orisirisi ede, Faransé, Geesi, ede Sipeeni, sugbon ko wa ni ede Yoruba. Boya nigbamii, o ma yipada be, sugbon won nilo awon onitumo Yoruba fun be. Pelu Scratch awon omodé won le kọ́ ati gbadun ni akoko kanna.