Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Indonésíà Republic of Indonesia
Republik Indonesia |
|---|
| | |  | Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ | Jakarta |
|---|
| Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Indonesian |
|---|
| Orúkọ aráàlú | Indonesian |
|---|
| Ìjọba | Orile-ede olominira aareonipiparapo |
|---|
| | Prabowo Subianto |
|---|
| Gibran Rakabuming Raka |
|---|
| | Ilominira |
|---|
| Ìtóbi |
|---|
| 1,904,569 km2 (735,358 sq mi) (16k) |
|---|
| 4.85 |
|---|
| Alábùgbé |
|---|
• 2009 estimate | 229,965,000[2] (4k) |
|---|
• 2000 census | 206,264,595 |
|---|
• Ìdìmọ́ra | 119.8/km2 (310.3/sq mi) (84k) |
|---|
| GDP (PPP) | 2010 estimate |
|---|
• Total | $1,027.279 billion[3] |
|---|
• Per capita | $4,379[3] |
|---|
| GDP (nominal) | 2010 estimate |
|---|
• Total | $670.421 billion[3] |
|---|
• Per capita | $2,858[3] |
|---|
| Gini (2002) | 34.3 medium |
|---|
| HDI (2007) | ▲ 0.734[4] Error: Invalid HDI value · 111th |
|---|
| Owóníná | Rupiah (IDR) |
|---|
| Ibi àkókò | UTC+7 to +9 (opo) |
|---|
| ko tele |
|---|
| Ojúọ̀nà ọkọ́ | òsì |
|---|
| Àmì tẹlifóònù | +62 |
|---|
| ISO 3166 code | ID |
|---|
| Internet TLD | .id |
|---|
|
Indonésíà (pípè/ˌɪndoʊˈniːziə/ tàbí/ˌɪndəˈniːʒə/), lóníbiṣẹ́ bíiOrílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Indonésíà (Àdàkọ:Lang-id), jẹ́ orílẹ̀-èdè níGúúsùìlàorùn Ásíà àtiOseania. Indonesia ní àwọnerékùṣù 17,508. Pẹ̀lú olùgbé bíi 230 ẹgbẹgbẹ̀rún ènìyàn, òhun ni orílẹ̀-èdèolólùgbéjùlọ kẹrin láyé, ó sì níolùgbé àwọn Mùsùlùmí tótóbijùlọ láyé. Indonésíà jẹ́orílẹ̀-èdè olómìnira, pẹ̀lú aṣòfin àti ààrẹ adìbòyàn. Olúìlú rẹ̀ niJakarta. Ó ní bodè ilẹ̀ mọ́Papua New Guinea,East Timor, àtiMalaysia. Àwọn orílẹ̀-èdè míràn ìtòsí rẹ̀ náà tún niSingapore,Philippines,Australia, àti ilẹ̀agbègbè ÍndíàAndaman and Nicobar Islands. Indonesia jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ olùdásílẹ̀ASEAN àti ọmọ egbẹ́Àwọn òkòwò únlá G-20.
Òṣùṣùerékùṣù Indonesia ti jẹ́ agbègbè òwò pàtàkì láti ọ̀rúndún keje, nígbàtíSrivijaya àtiMajapahit ṣòwò pẹ̀lúṢáínà àtiIndia. Díẹ̀díè àwọn olórí ibẹ̀ gba àpẹrẹ àṣà, ẹ̀sìn àti olóṣèlú láti òkèrè láti ìbẹ̀rẹ̀ àwọn ọ̀rúndún CE, bẹ́ẹ̀sìni àwọn ilẹ̀ọbaHindu àtiBuddhisti gbòòrò. Itan Indonesia ti gba ipa latodo awon alagbara okere ti won wa sibe nitori awon ohun alumoni toni. Awon musulumi onisowo mu esinIslam wa sibe, beesini awon alagbara lati Europe ba ara won ja lati se adase owo ni awon Erekusu SpiceMaluku lasikoIgba Iwari. Leyin awon orundun meta ati aboiseamusin awon ara Hollandi, Indonesia gba ilominira re leyinOgun Agbaye 2k. Loni Indonesia je orile-ede olominira aareoniparapo to niawon igberiko meta le logbon.
Kakiri awon opo erekusu re, Indonesia ni awon eya eniyan, ede ati esin otooto.Awon ara Java ni eya eniyan totobijulo, to si unbori loloselu. Indonesia ti sedagbasoke idamo kanna to ni ede orile-ede, orisi eya-eniyan, iseopo esin larin ogunlogo olugbe musulumi, ati itan iseamuin ati bi won se koju re.Motto orile-ede Indonesia,"Bhinneka Tunggal Ika" ("Okan ninu Opo"), tokasi awon opo orisirisi to da orile-ede yi. Botilejepe o ni olugbe pupo ati awon agbegbe sisupo ololugbe, Indonesia ni awon agbegbe aginju to niopoelemin giga keji lagbaye. Botilejepe o ni awon ohun alumoni ile pupo aini unba ja gidigidi loni.[5]
OrukoIndonesia wa lati LatiniIndus, ati Girikinesos, to tumosi "erekusu".[6] Oruko yi lojo lati orundun 18k, ki Indonesia alominra o to je didasile.[7] Ni 1850, George Earl,onimo oro-eyaeniyan omo Geesi, damoran lilo oroIndunesians — atiMalayunesians — fun awon onibugbe "Osusuerekusu India tabi Osusuerekusu Malaya".[8] Ninu iwe yi kanna, akeko Earl,James Richardson Logan, loIndonesia gege bi oro-oruko kanna funOsusuerekusu India.[9] Sibesibe awon olukowe ara Hollandi ninuawon iwe lori East Indies won ko loIndonesia. Dipo, won loOsusuerekusu Malay (Maleische Archipel); theNetherlands East Indies (Nederlandsch Oost Indië), tabiIndië;Ilaorun (de Oost); atiInsulinde.[10]
lati 1900,Indonesia bere sini wopo bi oruko ninu awon iwe olukowe lodi awon Nedalandi, beesini awon asetorile-ede gba ni lilo gege bi ifihan oselu.[11]Adolf Bastian, lati Yunifasiti ilu Berlin, mugbajumo pelu iwe reIndonesien oder die Inseln des Malayischen Archipels, 1884–1894. Olukowe ara Indonesia to koko lo oruko yi niSuwardi Suryaningrat (Ki Hajar Dewantara), nigbato da iso akede sile ni Nedalandi pelu orukoIndonesisch Pers-bureau ni 1913.[7]
- ↑US Library of Congress; Vickers (2005), page 117.
- ↑Department of Economic and Social AffairsPopulation Division (2009) (PDF). World Population Prospects, Table A.1. 2008 revision. United Nations. http://www.un.org/esa/population/publications/wpp2008/wpp2008_text_tables.pdf. Retrieved 12 March 2009.
- ↑3.03.13.23.3"Indonesia". International Monetary Fund. Retrieved21 April 2010.
- ↑"Human Development Report 2009. Human development index trends: Table G"(PDF). The United Nations. Retrieved5 October 2009.
- ↑Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref> tag; no text was provided for refs namedeconomist1 - ↑Tomascik, T; Mah, J.A., Nontji, A., Moosa, M.K. (1996). The Ecology of the Indonesian Seas – Part One. Hong Kong: Periplus Editions Ltd.. ISBN 962-593-078-7.
- ↑7.07.1Àdàkọ:Id iconAnshory, Irfan (16 August 2004). "Asal Usul Nama Indonesia". Pikiran Rakyat. Archived fromthe original on 15 December 2006. https://web.archive.org/web/20061215190155/http://www.pikiran-rakyat.com/cetak/0804/16/0802.htm. Retrieved 5 October 2006.
- ↑Earl, George S. W. (1850). "On The Leading Characteristics of the Papuan, Australian and Malay-Polynesian Nations". Journal of the Indian Archipelago and Eastern Asia (JIAEA): 119.
- ↑Logan, James Richardson (1850). "The Ethnology of the Indian Archipelago: Embracing Enquiries into the Continental Relations of the Indo-Pacific Islanders". Journal of the Indian Archipelago and Eastern Asia (JIAEA): 4:252–347. ;Earl, George S. W. (1850). "On The Leading Characteristics of the Papuan, Australian and Malay-Polynesian Nations". Journal of the Indian Archipelago and Eastern Asia (JIAEA): 254, 277–278.
- ↑(This term was introduced in 1860 in the influential novelMax Havelaar (1859), written byMultatuli, critical of Dutch colonialism).Justus M. van der Kroef (1951). "The Term Indonesia: Its Origin and Usage". Journal of the American Oriental Society 71 (3): 166–171. doi:10.2307/595186. http://links.jstor.org/sici?sici=0003-0279%28195107%2F09%2971%3A3%3C166%3ATTIIOA%3E2.0.CO%3B2-5.
- ↑Jusuf M. van der Kroef (1951). "The Term Indonesia: Its Origin and Usage". Journal of the American Oriental Society 71 (3): 166–171. doi:10.2307/595186. http://links.jstor.org/sici?sici=0003-0279%28195107%2F09%2971%3A3%3C166%3ATTIIOA%3E2.0.CO%3B2-5.