Movatterモバイル変換


[0]ホーム

URL:


Jump to content
Wikipedia
Ṣe àwáàrí

Georg Ohm

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Georg Simon Ohm
Ìbí(1789-03-16)16 Oṣù Kẹta 1789
Erlangen,Germany
Aláìsí6 July 1854(1854-07-06) (ọmọ ọdún 65)
Munich,Germany
IbùgbéGermany
Ọmọ orílẹ̀-èdèGerman
PápáPhysics
Ilé-ẹ̀kọ́University of Munich
Ibi ẹ̀kọ́University of Erlangen
Doctoral advisorKarl Christian von Langsdorf
Ó gbajúmọ̀ fúnOhm's law
Ohm's phase law
Ohm's acoustic law
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síCopley Medal (1841)

Georg Simon Ohm (16 March 1789 – 6 July 1854) jeasefisiksi araJemani. Gege bi oluko ni ile-eko agba, Ohm bere iwadi re peluahamo elektrokemika to sese je didawaye, ti ara Italia OloyeAlessandro Volta dawaye. Pelu awon irin-ise to da fun ra re, Ohm wadaju pe iseepin taara wa lariniyato alagbara (potential difference tabivoltage nièdè Gẹ̀ẹ́sì) to je mimulo rekojaopa agbena kan atiiwo onitanna to waye. Ibasepo yi lamo loni siOfin Ohm.


Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí.

Ẹ lefẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ látifẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ.

Itokasi

[àtúnṣe |àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/w/index.php?title=Georg_Ohm&oldid=468350"
Àwọn ẹ̀ka:
Ẹ̀ka bíbòmọ́lẹ̀:

[8]ページ先頭

©2009-2025 Movatter.jp