Movatterモバイル変換


[0]ホーム

URL:


Jump to content
Wikipedia
Ṣe àwáàrí

Gánà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Gánà
Republic of Ghana

Flag of Gánà
Àsìá
Àmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ Gánà
Àmì ọ̀pá àṣẹ
Motto: "Freedom and Justice"
Location of Gánà
Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Accra
5°33′N0°12′W / 5.550°N 0.200°W /5.550; -0.200
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaEnglish[2][3]
Lílò national languagesBritish English (official Language)
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn
(2010[4][5])
Orúkọ aráàlúGhanaian
Ìjọba
John Mahama
Jane Naana Opoku-Agyemang
AṣòfinParliament
Independencefrom theUnited Kingdom
6 March 1957
1 July 1960
28 April 1992
Ìtóbi
• Total
239,567 km2 (92,497 sq mi) (80th)
• Omi (%)
4.61 (11,000 km; 4,247 mi2)
Alábùgbé
• 2016 estimate
28,308,301[6] (45th)
• 2010 census
24,200,000[7]
• Ìdìmọ́ra
101.5/km2 (262.9/sq mi) (103rd)
GDP (PPP)2019 estimate
• Total
$211.127 billion[8]
• Per capita
$6,998[8]
GDP (nominal)2018 estimate
• Total
$68 billion[8]
• Per capita
$2,262[8]
Gini (2012)42.4[9]
medium
HDI (2017) 0.592[10]
medium · 140th
OwónínáGhanaian cedi (GHS)
Ibi àkókòUTC+0 (GMT)
Ojúọ̀nà ọkọ́right
Àmì tẹlifóònù+233
ISO 3166 codeGH
Internet TLD.gh

GánàIPA: [gá.nà], jẹ́ orílẹ̀-èdè níìhà ìwọ̀-oòrùn ilẹ̀Afíríkà. Ní ìfọwọ́sí ''Republic ofGhana", jẹ́ orílẹ̀-èdè kan pẹ̀lú Gulf of Guinea àti Òkun Àtìláńtíìkì, ní orílẹ̀-èdè Ìwọ̀-oòrun Afíríkà. Gbígbà ibi-ilẹ̀ kan ti 238,535 km2 (92,099 sq mi),Gánà ń ko Ivory Coast ní ìwọ̀-oòrun, Burkina Faso ní àríwá, Tógò ní ìlà-oòrun, àti Gulf of Guinea àti Òkun Àtìláńtíìkì ní gúúsù. ÌlúGánà túmọ̀ sí "Ọba Ajagun" ní èdè Soninke.[11]

Ìpínlẹ̀ àkọ́kọ́ tí ó wà títí ní agbègbèGánà lónìí láti ọjọ́ kẹsàn-án ọdún 11 jẹ́,Ìpínlẹ̀ Bọ́nò ti ọ̀dúnrún náà.[12] Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ìjọba àti àwọn ìjọba tó fara hàn ní àwọn ọ̀rúndún, èyí tó lágbára jù lọ ni ìjọba Dagbon[13] ati ìjọba Àṣáńtì.[14] Láti ọdún karùn-úndínlógún, ìjọba Ìlú Potogí, pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè alágbára Yúróòpù mìíràn lẹ́yìn, díje agbègbè nítorí ìṣòwò, títí tí Ìjọba Gẹ̀ẹ́sì fi ìdí múlẹ̀ ìṣàkóso etíkun ní òpin ọdún 19k. Lẹ́yìn ọgọ́rùn-ún ọdún atakò ti àwọn ọmọ abínibí, ohun tí ó jẹ́ ààlàGánà ní báyìí tẹ̀ lé ààlà tí èyí tí ó jẹ́ agbègbè ìjọba amúnisìn Gẹ̀ẹ́sì mẹ́rin ọ̀tọ̀tọ̀: Gold Coast,Àṣáńtì, Àwọn Agbègbè Àríwá àti Ilẹ̀ Tógò Gẹ̀ẹ́sì. Àwọn wọ̀nyí ni ìṣọ̀kan gẹ́gẹ́ bí ìjọba olómìnira láàárín Ìjọba àpapọ̀ Gẹ̀ẹ́sì ní oṣù kẹta, ọjọ́ kẹfà, ọdún 1957.[15][16][17]

OlùgbéGánà tó tó mílíọ̀nù 30[18] ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ẹ̀yà, èdè àti ẹ̀sìn àwọn ẹgbẹ́. Gẹ́gẹ́ bí ìkànìyàn ti 2010, 71.2% orílẹ̀-èdè jẹ́ onígbàgbọ́, 17.6% jẹ́ Mùsùlùmí, àti 5.2% jẹ́ onísìn ìbílẹ̀ tàbí kò sí ẹ̀sìn.[19] Onírúurú ilẹ̀ àti ìmọ̀-jìnlẹ̀ ti àwọn sàkánì láti ọ̀dàn etíkun sí igbó kìjikìji olóoru.

Orílẹ̀-èdèGánà jẹ́ ìjọba tiwantiwa t’orílẹ̀-ede kan tó jẹ́ olùdarí nípasẹ̀ adarí kan tó jẹ́ orí orílẹ̀-èdè àti olórí ìjọba.[20] Ìdàgbàsókè ètò-ọrọ̀ ti ń múGánà dàgbà, ètò òṣèlú tiwantiwa sì ti jẹ́ kí Gánà jẹ́ orílẹ̀-èdè alágbára ní agbègbè òun ní Ìwọ̀-oòrùn Afíríkà.[21] Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ti Non-Aligned Movement,Ìṣọ̀kan Afíríkà (AU),Àgbàjọ Tòkòwò àwọn Orílẹ̀-èdè Ìwọ-oòrùn Afíríkà (ECOWAS), Ẹgbẹ́ 24 (G24) àti Àgbáyé ti Àwọn Orílẹ̀-èdè.[22]

Ìtàn

[àtúnṣe |àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ère alámọ̀ Akan ti ọ̀dúnrún 16k, Metropolitan Museum of Art,Gánà
Máàpù ọdún 1850 tó fi ọmọ Akan ÌjọbaÀṣáńtì nínú ìhà Gínì àti ẹkùn àyíká ní ìwọ̀-oòrùn Afíríkà hàn
Ọnà onídẹ Àṣáńtì ti ọ̀rúndún 18k tí wọ́n pè níkuduo. Eruku wúrà àti ègé wúrà ni wọ́n fi pamọ́ nínúkuduo, àti ohun ìní míì náà. Gẹ́gẹ́ bí kóló fúnkra ( ipá ìwàláàyè) ẹni tó ní i,kuduo ṣe kókó nínú ayẹyẹ fún bíbọ̀ onítọ̀hún.

A mọGánà gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan nínú àwọn ìjọba ńlá ní Bilad el-Sudan nípasẹ̀ ọ̀rúndún kẹsàn-án.[23]

Orílẹ̀-èdèGánà ni ó wà láàárín ogoro àti Ọjọ-iwari nípasẹ̀ ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ìjọba Akan tó borí púpọ̀ jù lọ ní àwọn agbègbè Gúúsù ati Àárín gbùngbùn. Èyí pẹ̀lú Ottoman Àṣáńtì, Akwamu, Bonoman, Denkyira, ati ijọba Mankessim.[24]

Bó tilẹ̀ jẹ́ pé agbègbè tiGánà òde òní ni Ìwọ̀-oòrun Afíríkà ti ní ìrírí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn àgbéká olùgbé, àwọn Akan ti fìdí rẹ̀ múlẹ̀ ní ọ̀rúndún karùn-ún.[25][26] Ní ìbẹ̀rẹ̀ ọ̀rúndún 11k, àwọn Akan ti fìdí rẹ̀ múlẹ̀ nílùú Akan tí wọ́n pè ní Bonoman, èyí tí a dárúkọ Ekun Brong-Ahafo.[25][27]

Láti ọ̀rúndún kẹẹ̀dógún, àwọn ọmọ Akan ti inú ohun tí a gbàgbọ́ pé ó ti jẹ́ agbègbè Bonoman, láti ṣẹ̀dá ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ìlú Akan tiGánà, ní àkọ́kọ́ dá lórí òwò wúrà.[28] Àwọn ìpínlẹ̀ wọ̀nyí pẹ̀lú Bonoman (Ẹkùn Brong-Ahafo), Àṣáńtì (Ẹkùn Àṣáńtì), Denkyira (Ẹkùn Ìwọ̀-oòrùn Àríwá), ìjọba Mankessim (Ẹkùn Àárín gbùngbùn),àati Akwamu (agbègbè Ìlà-oòrun). Ní ọdún 19k, agbègbè ti ìhà gúúsù ti Gánà ni ó wà nínú ìjọba Àṣáńtì, ọ̀kan nínú àwọn ìpínlẹ̀ tó lágbára jù lọ ní ìhà aṣálẹ̀ Afíríkà ṣáájú ìbẹ̀rẹ̀ ètò amúnisìn.[25]

Ìjọba Àṣáńtì ṣiṣẹ́ ní ìṣáájú lọ́nà tí kò súnmọ́ tímọ́tímọ́, àti níkẹ̀yìn bí ìjọba àjùmọ̀ṣe pẹ̀lú ìlọsíwájú, iṣẹ́-ṣíṣe ayọ́gínní tó ga jù lọ tó dá ní olú-ìlúKumasi.[25] Ṣáájú ìbáṣepọ̀ Akan pẹ̀lú àwọn òyìnbó, àwọn èèyàn Akan ti ṣẹ̀dá ètò-ọrọ̀ tó ní ìlọsíwájú tó dá lé lórí pàtàkì wúrà àwọn ọjà oníwúrà tí wọ́n tà sáwọn ìlú Afíríkà.[25][29]

Àwọn ìjọba àkọ́kọ́ tí a mọ̀ láti fara hàn nílùú Gánà ti òde òní ni àwọn ìlú Mole-Dagbani. Mole-Dagomba gẹṣin wá láti Burkina Faso ti òde òní lábẹ́ adarí Naa Gbewaa nìkan.[30] Pẹ̀lú àwọn ohun ìjà tó já fáfá àti tó dá lórí aláṣẹ àárín gbùngbùn kan, wọ́n tètè gbógun tì wọ́n sì tẹ̀ dó sí ilẹ̀ èèyàn agbègbè Tendamba (àwọn àlùfáà ọlọ́run ilẹ̀) wọ́n ṣàkóso wọn, wọ́n sì fi ìdí wọn múlẹ̀ gẹ́gẹ́ bí aláṣẹ lórí àwọn abínibí, wọ́n fi Gambaga jọba.[31] Ikú Naa Gbewaa fa ìjà abẹ́lé láàárín àwọn ọmọ rẹ̀, díẹ̀ nínú àwọn tó kúrò láti tẹ̀ dó àwọn ìjọba ọ̀tọ̀tọ̀ pẹ̀lú Dagbon, Mamprugu, Mossi, Nanumba àti Wala.

Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí.

Ẹ lefẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ látifẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ.


Itokasi

[àtúnṣe |àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Emefa.myserver.org". Archived fromthe original on 26 April 2012. Retrieved21 December 2010. 
  2. "Language and Religion". Ghana Embassy.Archived from the original on 1 March 2017. Retrieved8 January 2017.English is the official language of Ghana and is universally used in schools in addition to nine other local languages. The most widely spoken local languages are, Ga, Dagomba, Akan and Ewe. 
  3. "Ghana – 2010 Population and Housing Census"(PDF).Government of Ghana. 2010. Archived fromthe original(PDF) on 25 September 2013. Retrieved1 June 2013. 
  4. "Ghana – 2010 Population and Housing Census"(PDF).Government of Ghana. 2010. Archived fromthe original(PDF) on 25 September 2013. Retrieved1 June 2013. 
  5. "People > Ethnic groups: Countries Compared". NationMaster.Archived from the original on 14 July 2014. Retrieved22 July 2014. 
  6. "2010 Population Projection by Sex, 2010–2016". Ghana Statistical Service. Archived fromthe original on 24 April 2018. Retrieved2 May 2018. 
  7. Antoinette I. Mintah (2010). 2010 Provisional Census Results Out. 4 February 2011. Population Division, Ghana Government. Archived fromthe original on 15 June 2011. https://web.archive.org/web/20110615141322/http://www.ghana.gov.gh/index.php?option=com_content&view=article&id=4712%3A2010-provisional-census-results-out&catid=88%3Adaily-news-summary&Itemid=236. Retrieved 7 February 2011. 
  8. 8.08.18.28.3"Report for Selected Countries and Subjects".www.imf.org. Retrieved25 May 2019. 
  9. "GINI index (World Bank estimate)".data.worldbank.org.World Bank.Archived from the original on 25 January 2019. Retrieved24 January 2019. 
  10. "2018 Human Development Report". United Nations Development Programme. 2018.Archived from the original on 14 September 2018. Retrieved14 September 2018. 
  11. Jackson, John G. (2001)Introduction to African Civilizations, Citadel Press, p. 201,ISBN 0-8065-2189-9.
  12. Meyerowitz, Eva L. R. (1975) (in en). The Early History of the Akan States of Ghana. Red Candle Press. https://books.google.com/books?id=F3lyAAAAMAAJ. 
  13. Danver, Steven L (10 March 2015). Native Peoples of the World: An Encyclopedia of Groups, Cultures and Contemporary Issues. Routledge. pp. 25. ISBN 978-1-317-46400-6. https://books.google.com/books?id=vf4TBwAAQBAJ&pg=PA25&dq=Kingdom+of+Dagbon#q=Kingdom%20of%20Dagbon. 
  14. "Asante Kingdom".Afrika-Studiecentrum, Leiden. Archived fromthe original on 12 July 2014. RetrievedOctober 8, 2020. Unknown parameter|url-status= ignored (help)
  15. Àdàkọ:Cite video
  16. "First For Sub-Saharan Africa". BBC. Archived fromthe original on 1 November 2011. RetrievedOctober 8, 2020. Unknown parameter|url-status= ignored (help)
  17. "Exploring Africa – Decolonization". exploringafrica.matrix.msu.edu. Archived fromthe original on 2 June 2013. RetrievedOctober 8, 2020. Unknown parameter|url-status= ignored (help)
  18. "Ghana Population (2019) – Worldometers".www.worldometers.info (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived fromthe original on 17 September 2018. RetrievedOctober 8, 2020. Unknown parameter|url-status= ignored (help)
  19. "2010 Population & Housing Census: National Analytical Report"(PDF). Ghana Statistical Service. 2013. p. 63. Archived fromthe original(PDF) on 12 July 2018. RetrievedOctober 8, 2020. Unknown parameter|url-status= ignored (help)
  20. CIA World FactBook."Ghana".CIA World FactBook. CIA World FactBook. Archived fromthe original on 15 November 2013. Retrieved October 8. 2020. Unknown parameter|url-status= ignored (help);Check date values in:|access-date= (help)
  21. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid<ref> tag; no text was provided for refs namedSouth America and West Africa
  22. "Ghana-US relations".United States Department of State. 13 February 2013. Archived fromthe original on 5 April 2013. RetrievedOctober 8, 2020. Unknown parameter|url-status= ignored (help)
  23. Levtzion, Nehemia (1973). Ancient Ghana and Mali. New York: Methuen & Co Ltd. p. 3. ISBN 978-0-8419-0431-6. 
  24. Title: Africa a Voyage of Discovery with Basil Davidson, Language: English Type: Documentary Year: 1984 Length: 114 min.
  25. 25.025.125.225.325.4"Pre-Colonial Period". Ghanaweb.com. Archived fromthe original on 23 November 2010. RetrievedOctober 8, 2020. Unknown parameter|url-status= ignored (help)
  26. "Pre-European Mining at Ashanti, Ghana"(PDF) (PDF). Pdmhs.com. October 1996. Archived fromthe original(PDF) on October 8, 2020. RetrievedOctober 8, 2020. Unknown parameter|url-status= ignored (help)
  27. Tvedten, Ige; Hersoug, Bjørn (1992). Fishing for Development: Small Scale Fisheries in Africa. Nordic Africa Institute. pp. 60–. ISBN 978-91-7106-327-4. https://books.google.com/books?id=Itt1hIbsbQsC&pg=PA60. Retrieved October 8, 2020. 
  28. The Techiman-Bono of Ghana: an ethnography of an Akan society Kendall/Hunt Pub. Co., 1975
  29. "A Short History of Ashanti Gold Weights". Rubens.anu.edu.au. Archived fromthe original on 2 September 2013. RetrievedOctober 8, 2020. Unknown parameter|url-status= ignored (help)
  30. Jessica W (15 November 2011)."Invasion of the Peoples of the North". GhanaNation. Archived fromthe original on 8 July 2014. RetrievedOctober 8, 2020. Unknown parameter|url-status= ignored (help)
  31. Curtis M. (19 November 2011)."Ghana Articles: Dagomba". GhanaNation.com. Archived fromthe original on 19 October 2014. RetrievedOctober 8, 2020. Unknown parameter|url-status= ignored (help)
Àwọnorílẹ̀-èdè apàṣẹ
Algeria ·Angola ·Benin ·Botswana ·Burkina Faso ·Burundi ·Cameroon ·Cape Verde ·Central African Republic ·Chad ·Comoros ·Democratic Republic of the Congo ·Republic of the Congo ·Côte d'Ivoire (Ivory Coast) ·Djibouti ·Egypt ·Equatorial Guinea ·Eritrea ·Ethiopia · France(Mayotte ·Réunion) ·Gabon ·The Gambia ·Ghana ·Guinea ·Guinea-Bissau · Italy(Pantelleria) ·Kenya ·Lesotho ·Liberia ·Libya ·Madagascar ·Màláwì ·Mali ·Mauritania ·Mauritius ·Morocco ·Mozambique ·Namibia ·Niger ·Nigeria · Portugal(Madeira) ·Rùwándà ·São Tomé and Príncipe ·Senegal ·Seychelles ·Sierra Leone ·Somalia ·South Africa ·South Sudan(from 9 July 2011) · Spain(Canary Islands ·Ceuta ·Melilla ·Plazas de soberanía) ·Sudan ·Swaziland ·Togo ·Tanzania ·Tunisia ·Uganda · Yemen(Socotra) ·Zambia ·Zimbabwe
States with
limited recognition
Dependencies
Unclear sovereignty
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/w/index.php?title=Gánà&oldid=597633"
Àwọn ẹ̀ka:
Ẹ̀ka bíbòmọ́lẹ̀:

[8]ページ先頭

©2009-2025 Movatter.jp