Fránsíọ̀m tabiFrancium, mimo tele bieka-caesium atiactinium K,[akiyesi 1] jeapilese kemika to ni ami-idamoFr atinomba atomu 87. O ni ikan ninu awonodionina tokerejulo larin gbogbo awon apilese ti a mo, bakanna ohun ni apilese aladanidakeji tosowonjulo (leyinastatine). Fransiom je onide to jeradioalagbara giga to n jera si astatine,radium, atiradon. Gege bionide alkali, o niagbara elektroni kan.
Francium je wiwari latowoMarguerite Perey niFransi (nibi ti apilese yi ti ri oruko) ni 1939. Ohun ni apilese togbeyin ti o je wiwari ninuadanida, kanran jije sisopapo.[akiyesi 2] Lode yara ise-idanwo, francium sowon gidigidi, iye ipase je wiwari ninu alumoni aladaluuranium atithorium, nibi tiisotopu francium-223 ti n je didasile to si n je jijera bibaun. Iye to kere bi 20–30 g (ounce kan) lowa nigba yiowu kakiri inuigbeleAye; awon isotopu yioku je alasopapo yanyan. Iye titobijulo ti o je kikojo lai isotopu yiowu ni isupo bi awon atomu 10,000 (ti francium-210) ti won je didasaye gege bi efuufututugidi niStony Brook ni 1997.[1]
- ↑Actually the least unstable isotope, francium-223
- ↑Awon apilese alasopapo, bitechnetium, ti je wiwari ninu adanida.