Movatterモバイル変換


[0]ホーム

URL:


Jump to content
Wikipedia
Ṣe àwáàrí

Físíksì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Kini Fisiksi?

[àtúnṣe |àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ìkan nínú àwọn àyọkà lọ́rí
Sáyẹ́nsì
 

Físíksì (lati inu Ìmọ̀ aláàdánidá) tabiFisiki (Physics) jẹ́ ìmọ̀ sáyẹ́nsì tí ó ń ṣe ìwádíèlò ati awonokun ti won n je sise akiyesi ninuàdánidá.

Awononímọ̀ aláàdánidá n se iwadi isise atiawon ohun-ini eda aye to yi wa ka latiàwọn ẹ̀yà ara ti won n se gbogbo awon elo ti a mo (Ìmọ̀aláàdánidá ẹ̀yà ara, particle physics) titi de biàgbàlá-ayé se n wuwa bi odidi kan (ìmọ̀ìràwọ̀títò astronomy,ìmọ̀ìdáyé cosmology).

Ise imo aladanida ni lati wa awon ofin ijinle ti gbogbo awon ohun aladanida n tele.

Ko si iye igbedanwo to le fi han pe iro mi je tito, sugbon igbedanwo kan pere le fihan wipe o je aitoAlbert Einstein


Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí.

Ẹ lefẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ látifẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ.

    Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/w/index.php?title=Físíksì&oldid=598631"
    Ẹ̀ka:
    Ẹ̀ka bíbòmọ́lẹ̀:

    [8]ページ先頭

    ©2009-2026 Movatter.jp