Dẹ̀jọ Túnfúlù
Àwọn irinṣẹ́
Àpapọ̀
Ìtẹ́síìwé/ìkójáde
Ní àkànṣe iṣẹ́ míràn
| Dẹ̀jọ Túnfúlù | |
|---|---|
| Ọjọ́ìbí | Túndé Mákindé Tòkunbọ̀ ojọ́ Kẹtàlélọ́gbọ̀n oṣù Karùnún ọdún 1969 Abẹ́òkúta |
| Iṣẹ́ | òṣèré orí ìtàgé |
Túndé Mákindé Tòkunbọ̀ tí gbogbo ènìyàn mọ̀ síDẹ̀jọ Túnfúlù jẹ́ gbajúgbajà òṣèré orí ìtàgé tí a bí ní ojọ́ Kẹtàlélọ́gbọ̀n oṣù Karùnún ọdún 1969 (31-05-1969), sí ìdílé ọ̀gbẹ́ni Abbas Mákindé ní ìlúAbẹ́òkúta.[1][2][3]