Bangladesh (ìrànwọ́·ìkéde) (Bengali: বাংলাদেশ,pronounced [ˈbaŋlad̪eʃ];Bangladesh), fun ibise gege bi orile-edeOlominira Araalu ile Bangladesh (Bengali: গণপ্রজাতন্ত্রী বাংলাদেশGônoprojatontri Bangladesh) jeorile-ede kan niGuusu Asia. O nibode moIndia ni gbogbo awon egbe re ayafi fun bode kekere moBurma (Myanmar) ni guusuilaorun ati moEbado Bengal ni guusu. Lapapo mo ipinleWest Bengal ni India, o je agbegbe eya-edeBengal. OrukoBangladesh tumosi "Orile-ede ile Bengal" ni ede ibiseBengal.
Awon bode Bangladesh lowolowo loni je didasile peluipinya Bengal atiIndia ni 1947, nigbati agbegbe na diegbe apailaorun orile-ede tuntunPakistan. Sugbon, o pinsoto latiegbe apaiworun pelu 1,600 km (994 mi) ile India. Nitori idawaloto oloselu ati ede ati aisi okowo to fa isodi awon araalu siIwoorun Pakistan, to faogun fun ilominira ni 1971 ati idasile orile-ede Bangladesh. Leyin ilominira orile-ede tuntun yi koju iyan, ajalu eda ati aini togbale, ati wahala oselu atiigbajoba ologun. Ipadade oseluaraalu ni 1991 mu itoro ati idagbasoke okowo wa.
Bangladesh ni orile-edekeje to lopo eniyan julo ati ikan ninu awonorile-ede to lopo eniyan kikijulo laye pelu osuwon aini giga.Sibesibe, GDP ti enikookan ti di emeji lati 1975, be sini osuwon aini ti re bi 20% lati ibere awon odun 1990. Bangladesh je ikan ninu awon orile-ede ti a npe ni okowo "Next Eleven".Dhaka, oluilu re, ati awon gbongan igboro ilu miran kopa ninu idagbasoke yi.[6]
Fun jeografi, orile-ede yi gba ile oloraDelta Ganges-Brahmaputra be sini oun ni omoyale lododunojo monsoon atiiji birikiti. Bangladesh ni ile yepe eti-odo to gunjulo laye ni tiCox's Bazaar. Oselu re ni oseluaralu ile-asofin. Bangladesh je ikan ninuAjoni awon Orile-ede,OIC,SAARC,BIMSTEC, atiD-8. Gege biBanki Agbaye se sakiyesi ninu Oro nisoki Orile-ede re ni July 2005, Bangladesh ti ni ilosiwa gidi ni idagbasoke eniyan ni apaimookomooka, idogba ako/abo ni ile-eko ati iresile ipoju awon eniyan.[7] However, Bangladesh si nkoju awon isoro nla, ajakale iwaibaje awon oloselu ati osise ijoba, economic competition relative to the world, seriousoverpopulation, widespread poverty, and an increasing danger of hydrologic shocks brought on by ecological vulnerability toclimate change.
Awon isekuasaolaju ni agbegbeBengal loseyin de egberun merin odun,[8] nigbati ibe je titedo lowo awonDravidian,Tibeto-Burman, ati awonAustro-Asiatic. Orisun oroBangla" tabi "Bengal" ko je mimo, botilejepe won nigbagbo pe o wa latiBang, eya to n sede Dravidian to budo si agbegbe yi larin odun 1000 kJ.[9]