Movatterモバイル変換


[0]ホーム

URL:


Jump to content
Wikipedia
Ṣe àwáàrí

Báháráìnì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Kingdom of Bahrain

مملكة البحرين
Mamlakat al-Baḥrayn
Coat of arms ilẹ̀ Bahrain
Coat of arms
Orin ìyìn: بحريننا
Bahrainona
Our Bahrain
Location of Bahrain
Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Manama
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaArabic[1]
Ẹ̀sìn
Islam (Sunni)
Orúkọ aráàlúBahraini
ÌjọbaConstitutional Monarchy
• King
Hamad bin Isa Al Khalifah
• Queen
Sabika bint Ibrahim
Khalifah ibn Sulman Al Khalifah
Independence
• FromPortugal
1602
• FromPersia
1783[2][3]
December 16, 1971[4]
Ìtóbi
• Total
750 km2 (290 sq mi) (184th)
• Omi (%)
0
Alábùgbé
• Estimate
791,000[5] (159th)
• Ìdìmọ́ra
1,189.5/km2 (3,080.8/sq mi) (7th)
GDP (PPP)2008 estimate
• Total
$27.014 billion[6] (118th)
• Per capita
$34,662[6] (32nd)
GDP (nominal)2008 estimate
• Total
$21.236 billion[6] (96th)
• Per capita
$27,248[6] (3rd)
HDI (2007) 0.895[7]
Error: Invalid HDI value · 39th
OwónínáBahraini dinar (BHD)
Ibi àkókòUTC+3
Ojúọ̀nà ọkọ́right
Àmì tẹlifóònù973
ISO 3166 codeBH
Internet TLD.bh

Bahrain tabiIle-Oba BahrainNí ọdún 1995, àwọn ènìyàn tí ó ń gbé orílẹ̀-èdè yìí tó ẹgbẹ̀rún lọ́nà ẹ̀ẹ́dégbẹ̀ta àti ààbọ̀ (555,000). Èdè Lárúbááwá (Arabic) ni èdè ìjọba ní ibẹ̀. Àwọn èdè kan tún wà tí wọ́n ń sọ níbẹ̀. Àwọn èdè náà ni fáàsì (farsi) tí àwọn tí ó ń sọ ó ẹgbẹ̀rún méjìdínláàádọ́ta (48, 000); Úúdù (Urdu) tí àwọn tí ó ń sọ ọ́ tó ẹgbẹ̀rún lọ́nà ogún (20,000) àti àwọn èdè fílípíìnì (Phillipine) mìíràn tí àwọn tí ó ń sọ wọ́n tó ẹgbẹ̀rún lọ́nà ogún (20,000). Èdè Gẹ̀ẹ́sì ti ń gbayì ní ilẹ̀ yìí sí i gẹ́gẹ́ bí èdè òwò àti èdè ìṣe àbẹ̀wò sí ìlú (tourism).




Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí.

Ẹ lefẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ látifẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ.

Itokasi

[àtúnṣe |àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Article 2(The official language is Arabic.)
  2. "CIA World Factbook, "Bahrain"". Archived fromthe original on 2010-12-29. Retrieved2008-04-12. 
  3. " Bahrain ." Encyclopædia Britannica. 2008. Encyclopædia Britannica Online. 16 2008[1]
  4. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid<ref> tag; no text was provided for refs namedautogenerated8
  5. Department of Economic and Social AffairsPopulation Division (2009) (.PDF). World Population Prospects, Table A.1. 2008 revision. United Nations. http://www.un.org/esa/population/publications/wpp2008/wpp2008_text_tables.pdf. Retrieved 2009-03-12. 
  6. 6.06.16.26.3"Bahrain". International Monetary Fund. Retrieved2009-10-01. 
  7. "Human Development Report 2009: Bahrain". The United Nations. Retrieved2009-10-18. 
Àwọn orílẹ̀-èdè
States with limited recognition
Dependencies àti
Special Administrative Regions
Austrálíà
Orílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ará ilẹ̀ Ṣáínà
Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/w/index.php?title=Báháráìnì&oldid=575747"
Àwọn ẹ̀ka:
Ẹ̀ka bíbòmọ́lẹ̀:

[8]ページ先頭

©2009-2025 Movatter.jp