Angelina Jolie |
---|
 Jolie ní ọdún 2014 |
Ọjọ́ìbí | Angelina Jolie Voight 4 Oṣù Kẹfà 1975 (1975-06-04) (ọmọ ọdún 49) Los Angeles,California, U.S. |
---|
Orúkọ míràn | Angelina Jolie Pitt |
---|
Ọmọ orílẹ̀-èdè | |
---|
Iṣẹ́ | òsèbínrìn[1] oludari fíímù[2] |
---|
Ìgbà iṣẹ́ | 1982–present |
---|
Works | Awọn Akojọ |
---|
Olólùfẹ́ | |
---|
Àwọn ọmọ | 6 |
---|
Parent(s) | Marcheline Bertrand Jon Voight |
---|
Àwọn olùbátan | - James Haven
- Barry Voight
- Chip Taylor
|
---|
Awards | Awọn Akojọ |
---|
Angelina Jolie[3] (/dʒoʊˈliː/; tí orúkọ àbìsọ rẹ̀ ń jẹ́Angelina Jolie Voight[4] ní kíkún, wọ́n bi ní ọjọ́ kẹrìn, Oṣù Kẹfà ọdún 1975). Ó jẹ́ òṣerébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà. Bákan náà ni ó tún jẹ́ olótùú eré àti ẹlẹ́yinjú àánú. Ó ti gba àmì ẹ̀yẹ oríṣiríṣi bíEbun Akademi àti Golden Globe Awards mẹ́ta léra wọn. Òun ni wọ́n kà sí òṣèrébìnrin tí owó rẹ̀ wọ́n jù ní Hollywood.
Jolie kọ́kọ́ farahàn lórí tẹlifíṣàn gẹ́gẹ́ bí òṣerémọdé pẹ̀lú bàbá rẹ̀ Jon Voightínú kópa nínú eré
rẹ̀ nípa ti wọ́n kópa
Lookin' to Get Out (1982Ó, Ó sì bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré ṣíṣe ní pẹrẹu pẹ̀lú ṣíṣe àwọn fíìmù alábọ́dé biCyborg 2 (1993), ti o si bere si n fara han ninu awon ere olokan-o-jokan leyin igba naa bi,Hackers (1995). O si tun kopa ninu ere ayelujara biGeorge Wallace (1997) atiGia (1998). O si gba ani-eyeEbun Akademi fun osere amugbalegbe to dara julo fun ipa re ti o ko ninu oniseGirl, Interrupted ti odun 1999.
- ↑Colon, Beatriz (August 24, 2022)."Angelina Jolie's latest outing with rarely seen daughter Vivienne amid lawsuit revelation - details".HELLO!. RetrievedAugust 26, 2022.
- ↑"Angelina Jolie: I had my ovaries removed, preventively".CBS News. March 24, 2015. RetrievedAugust 26, 2022.
- ↑Respers France, Lisa (April 16, 2019)."Angelina Jolie and Brad Pitt are legally single".CNN. Archived fromthe original on May 24, 2021. RetrievedFebruary 8, 2022. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑"Angelina Jolie".Biography. 2018-03-27. Retrieved2022-08-22.
|
---|
1936–1950 | |
---|
1951–1975 | |
---|
1976–2000 | |
---|
2001–present | |
---|