Movatterモバイル変換


[0]ホーム

URL:


Jump to content
Wikipedia
Ṣe àwáàrí

Agbon

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Agbon

Igiagbon (Cocos nucifera ) jẹ eya igi ọpẹ ( Arecaceae ) ati eyaCocos kan soso ti o ku. Ohun ti a n pe ni "agbon "[1] le tọka si gbogbo igiagbon, koro eso,tabi eso. Oruko yii wa lati oruko "Coco' eyi ti o je oruko Aguda atijo ti o tumo si ori, tabi agbari.

Awọn itọkasi.

[àtúnṣe |àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Pearsall, J., ed (1999). "Coconut". Concise Oxford Dictionary (10th ed.). Oxford: Clarendon Press. ISBN 0-19-860287-1. 
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/w/index.php?title=Agbon&oldid=573823"

[8]ページ先頭

©2009-2025 Movatter.jp