Movatterモバイル変換


[0]ホーム

URL:


Jump to content
Wikipedia
Ṣe àwáàrí

Abdelmadjid Tebboune

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Abdelmadjid Tebboune
عبد المجيد تبون
Abdelmadjid Tebboune in 2019
8th President of Algeria
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
19 December 2019
Alákóso ÀgbàSabri Boukadoum (Acting)
Abdelaziz Djerad
AsíwájúAbdelaziz Bouteflika
16th Prime Minister of Algeria
In office
25 May 2017 – 15 August 2017
ÀàrẹAbdelaziz Bouteflika
AsíwájúAbdelmalek Sellal
Arọ́pòAhmed Ouyahia
Minister of Defence
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
19 December 2019
AsíwájúAhmed Gaid Salah (as Deputy Minister of Defense)
Abdelaziz Bouteflika
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí17 Oṣù Kọkànlá 1945 (1945-11-17) (ọmọ ọdún 80)
Mécheria, Algeria

Abdelmadjid Tebboune (Lárúbáwá:عبد المجيد تبون‎; ọjọ́ìbí 17 November 1945) ni olóṣèlú aráAlgeria tó jẹ́ lọ́wọ́lọ́wọ́ pé òhun niÀàrẹ ilẹ̀ Algeria láti December 2019. Ó rọ́pò ÀàrẹAbdelaziz Bouteflika àti Arọ́pò Olórí Orílẹ̀-èdè tẹ́lẹ̀Abdelkader Bensalah. Tẹ́ltẹ́lẹ̀, òhun ló jẹ́Alákósò Àgbà ilẹ̀ Algeria láti May 2017 di August 2017. Bákannáà, ó tún jẹ́ tẹ́lẹ̀ Alákóso Ètò Ilé láti 2001 di 2002 fún ọdún kan àti ní ẹ̀kan si láti 2012 di 2017 fún ọdún 5.[1]


Itokasi

[àtúnṣe |àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Lamlili, Nadia (2017-05-25). "Premier ministre d'Abdelaziz Bouteflika ?" (in fr). Jeune Afrique. Archived fromthe original on November 2, 2019. https://web.archive.org/web/20191102204034/https://www.jeuneafrique.com/442030/politique/algerie-abdelmadjid-tebboune-nouveau-premier-ministre-dabdelaziz-bouteflika/. Retrieved November 2, 2019. 
Ben Bella •vacant, 1963-79 •Abdelghani •Brahimi •Merbah •Hamrouche •Ghozali •Abdessalam •Malek •Sifi •Ouyahia •Hamdani •Benbitour •Benflis •Ouyahia •Belkhadem •Ouyahia
Flag of Algeria
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/w/index.php?title=Abdelmadjid_Tebboune&oldid=585287"
Àwọn ẹ̀ka:

[8]ページ先頭

©2009-2025 Movatter.jp