Afri ni oruko awon eniyan ti won gbe niAriwa Afrika lebaCarthage. Oruko awon wonyi je siso mo "afar" ti awonFiniki, to tumosi "eruku", sugbon ero 1981 kan[5] ti so pe o wa lati oro edeBerberifri tabi Ifran totumosi "cave", in reference to cave dwellers.[6] Afrika tabi Ifri tabi Afer[6] ni orukoBanu Ifran latiAlgeria atiTripolitania (EyaBerber tiYafran).[7]
Labe ijoba awon Ara Romu, Carthage di oluiluIgberiko Afrika, to tun je kikomo apa eba odoLibya oni. "-ka" ("ca") to je ilemeyin Afrika je awon Ara Romu to tokasi "orile-ede tabi ile".[8] Bakanna, ile-oba Musulumi ayeijounIfriqiya to wa leyin, ti a mo loni biTunisia, na tun lo iru oruko yi.
Awon orisun itumo miran ti won ti da laba bi orisun oruko ijoun "Afrika":
omo Ju olukoitan ni orundun 1stFlavius Josephus (Ant. 1.15) so pe o je sisoloruko funEpher, omokunrin omoomoAbraham gege bi Gen. 25:4, ti awon omomo re, bo se so, pe won bori Libya.
oro Griikiaphrike (Αφρική), to tumosi "aini otutu." OlukoitanLeo Africanus (1488–1554) lo damoran yi, to daba oro Griikiphrike (φρίκη, to tumosi "otutu ati eru"), lapapo mo "a-", lati tumosi "ile ti ko ni otutu ati eru.
Massey, ni 1881, mu orisun itumo kan wa lati oro Egyptiaf-rui-ka, "di dori ko ojuona Ka."Ka tokasi ibiomo. Nipa eyi Afrika je fun awon Ara Egypti, "ile ibimo."[9]
Ni ibereIgba Mesosoik, Afrika je jijapo mo awon orile Aye yioku gege biPangea.[10] Afrika pin awon fauna kanna ti orilegbangba yi ti o je sisori lowo awontheropods,prosauropods atiornithischians akokolo nigbatiigba Trias wa sopin.[10] Awon idokuta opin je wiwari kakiri Africa, sugbon won wopo ni guusu ju ariwa lo.[10] Ila to ya igba Triassic soto siJurassic lo falasi ibere awon isele iparun to ni ip ni lagbaye, botilejepe strata Afrika igba yi ko ti je gbigbewo daada.[10]
Awonipele ile igbaIbere Jurassik pinkiri lona kanna bi ti isunLate Triassic, with more common outcrops in the south and less common fossil beds which are predominated by tracks to the north.[10] As the Jurassic proceeded, larger and more iconic groups ofdinosaurs likesauropods andornithopods proliferated in Africa.[10]Middle Jurassic strata are neither well represented nor well studied in Africa.[10] Late Jurassic strata are also poorly represented apart from the spectacularTendaguru fauna inTanzania.[10] The Late Jurassic life of Tendaguru is very similar tothat found in western North America'sMorrison Formation.[10]
Afrika ki o to di ibialamusin o se e se ki o ni orisirisi orile-ede otooto to ju 10,000 lo ati asejoba[11] to ni orisirisi ilana ati agbajo oloselu. Ninu awon wonyi ni idipo ebi kekere awon asode bi awonSan ni apaguusu Afrika; titobi, awon adipo adimule bi awon idipo ibatan ebi awon eledeBantu ni apaarin ati apaguusu Afrika, awon adipo ibatan adimule gidigidi niIbi Iwo Ori Afrika, awonileoba Saheli titobi, ati awon ilu-orilejoba ati awon ileoba aladawa bi ti awonYoruba ni Iwoorun Afrika, ati awon ilu oja etiodo awonSwahili niIlaorun Afrika.
Nigba to fi di orundun 9k SK orisirisi awon orilejoba obairanderan, ti awon orilejobaHausa akoko wa ninu won, ti san kakiri saffana abe-sahara lati awon agbegbe apaiwoorun de ibiarin Sudan. Awon to lagbarajulo larin awon orilejoba wonyi niGhana,Gao, atiKanem-Bornu Empire. Agbara Ghana dinku ni orundun 11k sugbonIleobaluaye Mali ropo re, eyi lo si di opo gbogbo apaiwoorun Afrika mu ni orundun 13k. Kanem gba esin Imale ni orundun 11k. Be sini ni awon agbegbe igbo etiodo Iwoorun Afrika, awon ileoba alominira jadide laini ipa kankan latodo ariwaMusulumi.
Ashanti yam ceremony, 19th century by Thomas E. Bowdich
Ife, to je akoko larin awon ilu-orilejoba tabi ileobaYoruba, sedasile ijoba labeoba, ton unjeOoni.Ife je ibi pataki esin ati asa ni Afrika, ati fun asa ibile ere gbigbe. Iru ifijuwe ijoba Ile-Ife je gbigbamulo niOyo, nibiti awonoba, ti won unjeAlaafin ti figba kan joba lori opo iye iluorilejoba ati ileoba Yoruba miran ati ti awon ti won ko je Yoruba,IleobaDahomey awonFon je ibi ti won ko so ede Yoruba labe ijoba Oyo.
AwonAlmoraffidi, je obairanderanBeriberi latiSahara ti won fon kiri ariwaapaiwoorun Afrika ati peninsula Iberian nigba orundun 11k.[12]Banu Hilal atiBanu Ma'qil je akopo aon eyaArabBedouin latiArabian peninsula ti on kolo si iwoorun lati Egypt larin orundun 11k ati 13k.Ikoreokere fa idapo awon Arabu ati Beriberi, nibi ti awon ara ile ti diArabu,[13] be sini asa Arabu gba apilese asa ibile ibe, labe isokan Islam.[14]
Àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n wà ní ìpele yí ni wọ́n wà lábẹ́ àtòscheme for geographic subregions tí àjọ United Nations, àti data tí ó rọ̀ mọ́ ìtọ́ka sí fún àpilẹ̀kọ. Where they differ, provisos are clearly indicated.
↑10.010.110.210.310.410.510.610.710.8Jacobs, Louis L. (1997). "African Dinosaurs."Encyclopedia of Dinosaurs. Edited by Phillip J. Currie and Kevin Padian. Academic Press. pp. 2–4.
↑Egypt is generally considered atranscontinental country in Northern Africa (UN region) and Western Asia; population and area figures are for African portion only, west of theSuez Canal.
↑TheSahrawi Arab Democratic Republic is recognized as a sovereign state by theAfrican Union, however,Morocco claims the entirety of the country as Morocco's ownSouthern Provinces, and has occupied most of its territory since it declared its independence from Spain in 1976. Morrocco's occupation and annexation of this territory has not been recognized internationally.
↑The Spanishexclave ofCeuta is surrounded on land by Morocco in Northern Africa; population and area figures are for 2001.
↑The PortugueseMadeira Islands are often considered part of Northern Africa due to their relative proximity to Morocco; population and area figures are for 2001.
↑The Spanishexclave ofMelilla is surrounded on land by Morocco in Northern Africa; population and area figures are for 2001.
↑Bloemfontein is the judicial capital of South Africa, whileCape Town is its legislative seat, andPretoria is the country's administrative seat.