Movatterモバイル変換


[0]ホーム

URL:


Jump to content
Wikipedia
Ṣe àwáàrí

Áárọ́nì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Áárọ́nì

NínúBíbélì,Áárọ́nì ni ègbónMósè. Òun ni ó se èkejì Móósè gégé bí olórí fún àwon ara Isiréélì nígbà tí wón n la aginjù kojá tí wón n lo sí ilè ìlérí láti Íjíbíìtì. Wón n lo sí ilè ìlérí Kénáànì. Òun ni ó se èrè àgùntàn onígóòlù fún won. Ó kú ní orí òkè Hor nígba tí ó di omo odún métàlélógófà.



Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí.

Ẹ lefẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ látifẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ.

Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/w/index.php?title=Áárọ́nì&oldid=536818"
Ẹ̀ka:
Ẹ̀ka bíbòmọ́lẹ̀:

[8]ページ先頭

©2009-2025 Movatter.jp