Movatterモバイル変換


[0]ホーム

URL:


Jump to content
Wikipedia
Ṣe àwáàrí

Àsìá ilẹ̀ Gùyánà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Guyana
NameThe Golden Arrowhead
UseNational flag
Proportion3:5
Adopted26 May 1966[1]
DesignA green field with the black-edged red isosceles triangle based on the hoist-side superimposed on the larger white-edged golden triangle, also based on the hoist-side, pointed toward the fly-side.
Designed byWhitney Smith
Variant flag of Guyana
UseNational ensign
Proportion1:2
DesignAn elongated version of the above.
Variant flag of Guyana
UseCivil air ensign
Proportion7:11
DesignBritish Civil Air Ensign combined with national flag of Guyana. May be flown at airports and from landed aircraft.

Àsìá ilẹ̀ Gùyánà Jẹ́ àsíá orílẹ̀-édé, ó jẹ̀àmì òpá áṣẹ àti ogun. Àsíá yìí jẹ́ aláwọ̀ márùn ùn; Pupa, Funfun, Èsúrú, Dúdú àti awọ̀ Ewéko. Áwọ̀ pupa tí ó dúró fún àyípadà dáradára, àwọ̀ funfun tí ó dúró fún odò àti omi kanga tí ó mọ́ , ésúrú tí ó dúró fún wààrà àti ọrọ̀ orílẹ̀-èdè náà, Dúdú dúró fún ìfaradà àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè náà àti àwọ̀ ewéko tí ọ ó dúró fún ètò ọ̀gbìn tí ọ́ fi ẹsẹ̀ múlẹ̀.


Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí.

Ẹ lefẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ látifẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ.

àwọn ìtọ́ka sí

[àtúnṣe |àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Flag Dates: by month".fotw.info. 
Àwọn orílẹ̀-èdè
Àwọn agbègbè òkèrèàti agbègbè
1 Territories also in or commonly considered to be part ofÀríwá Amẹ́ríkà and/orÀrin Amẹ́ríkà2 Territories also in or commonly considered to be part ofAntarctica.
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/w/index.php?title=Àsìá_ilẹ̀_Gùyánà&oldid=587092"
Ẹ̀ka:
Ẹ̀ka bíbòmọ́lẹ̀:

[8]ページ先頭

©2009-2025 Movatter.jp