Movatterモバイル変換


[0]ホーム

URL:


Jump to content
Wikipedia
Ṣe àwáàrí

Ojúewé Àkọ́kọ́

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ẹ kú àbọ̀Wikipedia,
ìwé-ìmọ̀ọ̀fẹ́ẹnikẹ́ni le túnṣe.
01:15 (UTC);Ọjọ́rú,Ọjọ́ 26 Oṣù Ẹ̀rẹ̀nà ọdún2025
Àyọka35,126l'èdè Yorùbá.
Àwọn èbúté ·Àwọn ẹ̀ka ·Ìrànlọ́wọ́

Ìlànà ·Àwọn Ìbéèrè Wíwọ́pọ̀ ·Àgbàjọ ·Àwọn ìpinu ọ̀nà ìṣiṣẹ́ Wikipedia ·Ọrẹ ·WAP ·Ibi Ìṣojú (Embassy) ·Ìbápàdé

Adeniran Ogunsanya, amòfin àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Adeniran Ogunsanya, amòfin àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdèNàìjíríà

Adeniran OgunsanyaQC,SAN (31 January 1918 – 22 November 1996) jẹ́ amòfin àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdèNàìjíríà, tí ó sì tún jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára àwọn olùdásílẹ̀ ẹgbẹ́ òṣèlúIbadan Peoples Party (IPP). Ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí Kọmíṣọ́nà fún ètò ìdájọ́ ati ètò ẹ̀kọ́ fúnÌpínlẹ̀ Èkó ní àsìkò ìṣèjọba alágbádá ẹlẹ́kejì. Òun náà tún ni alága pátá pátá fún ẹgbẹ́ òṣèlúNigerian People's Party nígbà ayé rẹ̀.Wọ́n bí Adéníran ní ọjọ́ Kọkànlélógún oṣù Kíní ọdún 1918 ní agbègbèÌkòròdúÌpínlẹ̀ Èkó sí agboolé ọmọ Ọba Sùbérù Ògúnsànyà Ògúntádé tí ó jẹ́ Ọdọ̀fin ti ìlú Ìkòròdú nígbà náà. Adéníran lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ tiHope Waddell Training Institute ní ìlúCalabar nígbà tí ó ń gbé pẹ̀lú àbúrò bàbá rẹ̀ tí ó jẹ́ òṣìṣẹ́ ìjọba ní ìlú Calaba. Ìjọba fi ẹ̀bùn ẹ̀kọ́-ọ̀fẹ́ dá Adéníra lọ̀lá láti kàwé síwájú si ní ilé-ẹ̀kọ́King's College tí ó wà níÌpínlẹ̀ Èkó látàrí bí ó ṣe peregedé jùlọ pẹ̀lú máàkì tí ó ga jùlọ nínú ìdánwò àṣekágbá ti Standard VI (6) ní ọdún 1937. Ó tẹ̀ siwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀, tí ó sì kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìmọ̀ òfin ní ilé-ẹ̀kọ́ fásitì tiUniversity of Manchester àtiGray's Inn tí ó jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ ìmọ̀ òfin.

(ìtẹ̀síwájú...)

Che Guevara

  • ... péÌlú New York kọ́kọ́ jẹ́ pípè bi New Amsterdam?
  • ... péGuerrillero Heroico (aworan) tó jẹ́ àwòránChe Guevara ni "fọ́tò tógbajùmọ̀ jùlọ láyé"?
  • ... pé àwọn tóún tẹ̀lé ẹ̀sìnIslam úngbàdúràní 5 lójúmọ́?
  • ... péMars dà bí pupa nítoríìdóògún nínú àpáta rẹ̀ àti èruku lójúde rẹ̀?

Ẹ tún woÌròyìnWiki ní èdè Gẹ̀ẹ́sì

Gúnnungún Rüppell níNairobi National Park,Kenya.

Àwọn Iṣẹ́-ọwọ́ Míràn
Wikimedia Foundation ni ó gba àlejò Wikipedia, egbe-alasepo ti ki se fun ere ti o tun se alejo opo awonise-owo miran:
WikiàyásọWikiàyásọ
Àkójọ àwọn àmúsọ
Wikiatúmọ̀èdèWikiatúmọ̀èdè
Atúmọ̀èdè orísirísi èdè
WikispeciesWikispecies
Àkójọ àwọn irú ẹ̀dá
WikiìròyìnWikinews
Ìròyìn ọ́fẹ̀
WikisourceWikisource
Àwọn àkọsíìwé ọ̀fẹ́
CommonsWikimedia Commons
Àwòrán, ìró àti fídéò
WikifásítìWikifásítì
Èlò ìkọ́ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́
WikiìwéWikiìwé
Ìwéẹ̀kọ́ àti ìwéàwòṣe ọ̀fẹ́
Meta-WikiMeta-Wiki
Ibi àkóso ìṣẹ́-ọwọ́ Wikimedia
WikidataWikidata
Ìbùdó ìmò ọ̀fẹ́


Àṣà

Lítíréṣọ̀Eré-ìdárayáFílmùOrinTíátàÌṣeròyìnTẹlifísànRédíò

Tẹknọ́lọ́jì

Iṣẹ́ẹ̀rọInternetÀfigbébánisọ̀rọ̀Kọ̀mpútà

Àwùjọ

ẸbíFàájìÒfinỌ̀rọ̀-òkòwòÌnáwóÌṣèlúỌ̀rọ̀-àwùjọÈnìyànẸ̀kọ́Ìmòye

Sáyẹ́nsì

Ìtòràwọ̀ÒfurufúỌ̀gbìnSáyẹ́nsì kọ̀mpútàFísíksìÌwòsànÀdánidáKẹ́místrìBàíọ́lọ́jì

Mathimátíkì

Áljẹ́bràÌtúwòÌṣíròÌṣedọ́gbaJẹ́ọ́mẹ́trìNọ́mbàTẹ̀ọ́rẹ́mùỌgbọ́n

Jẹ́ọ́gráfì

AyéAdágúnOrílẹ̀-èdèÒkunOrílẹ̀ÌlúÁfríkàÁsíàEuropeGúúsù Amẹ́ríkàÀríwá Amẹ́ríkà

Ìtàn

OgunOrílẹ̀-èdè tẹ́lẹ̀Ilẹ̀ọbalúayéỌ̀rọ̀-ayéijọ́un

Ìgbésíayé

Olórí orílẹ̀-èdèOníṣọ̀nàÒṣeréOnímọ̀sáyẹ́nsìAmòyeOlóṣèlúOlùkọ̀wéOníṣòwò

Ẹ̀sìn àti ìgbàgbọ́

Ẹ̀sìn YorùbáÌmàleẸ̀sìn KrístìÌṣebúddhàÌṣehíndù

Ìlera

ÌmáralókunÌdárayáAmáralókunìtọ́jú ìleraÀrùnỌ̀rọ̀-àjàkálẹ̀àrùn

Wikipedia ní àwọn èdè míràn

Àwọn Wikipedia tí wọ́n ní ju àyọkà 1 000 000 lọ:
Deutsch (jẹ́mánì) ·English (gẹ̀ẹ́sì) ·Français (faransé) 

Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/w/index.php?title=Ojúewé_Àkọ́kọ́&oldid=586084"

[8]ページ先頭

©2009-2025 Movatter.jp